Mudashiru Lawal
Agbaọ́ọ̀lù ọmọ orílé-éde Nàìjíríà
A bi Mudashiru Babatunde "Muda" Lawal ni odun (8 June 1954 ni Abeokuta o ku ni 6 July 1991 ni ilu Ibadan) . O je agba boolu-arin boolu-elese ara fun orile ede Naijiria. Muda ni eni ti o ti figba kan ri sise atun-oko se nigba ti o sawari ebun gbigbaboolu afesegba,ti o si pinu yaan laayo gege bi ise oojo re. Won gba Mudashiru sinu agbaboolu agba | Super Eagle gege bi eni ti o le di aarin gbungbun mu fun awon akegbe re lori papa ni odun 1975. Bakan naa ni o tun darapo mo egbe agbaboolu ibile ti Shooting Stars F.C. ti o wa ni Ibadan.
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Mudashiru Babatunde Lawal | ||
Ọjọ́ ìbí | 8 June 1954 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Abeokuta, Nigeria | ||
Ọjọ́ aláìsí | 6 July 1991 | (ọmọ ọdún 37)||
Ibi ọjọ́aláìsí | Ibadan, Nigeria | ||
Playing position | Midfielder | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
1975-1984 | Shooting Stars F.C. | ||
1985-1986 | Stationery Stores F.C. | ||
1987-1988 | Abiola Babes | ||
1989-1991 | Shooting Stars F.C. | ||
National team | |||
1975-1985 | Nàìjíríà | 86 | (12) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |