Shooting Stars S.C.
Shooting Stars Sports Club (èyítí á n pè nì 3SC tàbí Oluyole Warriors) jẹ́ ẹgbẹ́ agbabọ́ọ́lù Nàìjíríà tí ọ wá ní Ìbàdàn, ní ilẹ̀ Nàìjíríà.
Full name | Shooting Stars Sports Club (3SC) | ||
---|---|---|---|
Nickname(s) | Oluyole Warriors | ||
Founded | 1950s (Bí WNDC Ibadan) | ||
Ground | Lekan Salami Stadium (Capacity: 10,000) | ||
Chairman | Hon. Babatunde Olaniyan | ||
Manager | Gbenga Ogunbote | ||
League | Nigeria Premier Football League | ||
2023-24 | 4th | ||
|
Ìtàn
àtúnṣeẸgbẹ́ náà jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ ìdíje Premier League ní Nàìjíríà ní ọdún 1972, nígbà tí wọ́n ń pè wọ́n WNDC Ìbàdàn (Western Nigeria Development Company), lẹ́yìn náà ni wọ́n pè wọ́n ní IICC (Industrial Investment and Credit Corporation) Shooting Stars tí Ìbàdàn.[1]
Ọrúkò wọ́n ní "Shooting Stars" ní á fí kún àbá àwọ́n ọ́mọ́ ẹgbẹ́ tí ọ dà ẹgbẹ́ náà, Olóògbé Jide Johnson atí Niyi Omowon, “Aare Odan Liberty” tí wọ́n gbàgbó pé àwọ́n òṣèré náà jẹ́ "iráwọ́" ní tiwọ́n.[2]
Shooting Stars jẹ́ ọ̀kan nínù àwọ́n ẹgbẹ́ bọ́ọ́lù tí wọ́n tẹlé jùlọ ní Nigeria. Wọ́n ṣé àwọ́n eré ilé wọ́n ní pápá iṣérè Lekan Salami. Oruko papa iṣérè náà ní orúkọ ọkàn lárá àwọ́n olólúfé ẹgbẹ́ agbabọ́ọ́lù tí ọ tí kú báyìí.
Shooting Stars ní ẹgbẹ́ àkọkọ́ tí ọ gbá ìfè ẹyẹ́ FA lórí ìpìlẹ ẹgbẹ́ ní Nigeria ní ọdún 1971, nígbàtí wọ́n ní àwọ́n òṣèré bíi Aderoju Omowon, Niyi Akande, Jossy Lad, Amusa Adisa.[3] Shooting Stars jẹ́ ọ̀kan nínù àwọ́n ẹgbẹ́ agbabọ́ọ́lù tí ọ ṣé ọṣọ jùlọ ní Nàìjíríà lẹ́gbẹ́ẹ́ Enyimba, Enugu Rangers atí Stationery Stores tí Èkó bótílẹ́jẹ́pé wọ́n tí kùnà láti bóri èyíkéyìí ìdíje pàtàkì láti ọdún 1998. Shooting Stars atí Enugu Rangers ní á mọ̀ sí àwọ́n ẹgbẹ́ bọ́ọ́lu ìbílè ní orílẹ-èdè náà, méjèèjì jẹ́ gábá lórí ààyè bọ́ọ́lu ní orílẹ-èdè náà ní àwọ́n ọdún 1970 atí 1980.[4]
3SC gbá idawọle àkọkọ́ tí CAF Cup, tí ṣẹ́gun Nakivubo Villa tí Uganda 3–0 ní ìparí ní pápá iṣérè Lekan Salami. Wọ́n gbá ifẹ ẹ̀yẹ African Cup Winners Cup ní 1976, di ẹgbẹ́ agbabọ́ọ̀lù Nàìjíríà àkọ́kọ́ tí ó gba ife ẹyẹ àgbáyé.[5]
Shooting Stars ní relegate sí ìsàlẹ̀ pípín ní 2006, ṣùgbọ́n gbá ìgbégá pàdà ní 2009. Wọ́n ní wọ́n relegate pàdà lórí àwọ́n tí ọ kẹhìn ọjọ́ tí àwọ́n 2017 NPFL àkókó..[5]
Ọpọ́lọ́pọ́ àwọ́n gbájugbájá ìràwọ tí ìlú òkèèrè tí ṣéré fún Shooting Stars ní iṣááju, pẹ̀lú agbabọ́ọ́lù afẹ́sẹgbá Afirika tẹ́lẹ̀ Rashidi Yekini, Segun Odegbami atí bẹ̀bẹ lọ́.[6][7]
Stadium atí ìṣàkóso
àtúnṣeShooting Stars n ṣé èrè ilé ní pápá iṣẹ̀rè Lekan Salami ní Adamasingba, Ìbàdàn. Gbenga Ogunbote ní wọ́n tí n kọ́ wọ́n.[8]
Ọlá gbá
àtúnṣe- Nigerian Premier League
- Aṣáju (5): 1976, 1980, 1983, 1995, 1998
- FA Cup
- Aṣáju (8): 1959, 1961, 1966, 1969, 1971 (bí WNDC), 1977, 1979, 1995
- CAF Cup
- Aṣáju: 1992
- African Cup Winners' Cup
- Aṣáju: 1976
- West African Clun the Championship
- Aṣáju: 1998
Àwọ́n ìtókásí
àtúnṣe- ↑ "BBC SPORT – Football – African – Living for 'Shooting'". news.bbc.co.uk (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 20 June 2017. Retrieved 17 October 2024.
- ↑ "About Ministry – Oyo State Government MDA" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-11-22. Retrieved 2024-10-17.
- ↑ "‘I locked up dead body of my daughter in a room and escaped". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-01-07. Archived from the original on 2022-11-22. Retrieved 2024-10-17.
- ↑ Omachonu, Kelvin (2024-06-16). "NPFL: Flying Enugu Rangers claim eighth league title". Soccernet.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-10-17.
- ↑ 5.0 5.1 "Shooting Stars have no reason to fail promotion bid, says Balogun". guardian.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-12-10. Retrieved 2024-10-17.
- ↑ "3SC History". shootingstarssc.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 17 October 2024.
- ↑ "Where are they now – The history making 1976 shooting stars squad?". guardian.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-11-03. Retrieved 2024-10-17.
- ↑ "Ogunbote signs 2-year contract extension as 3SC head coach". Sports Now (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 24 July 2024.