Mudashiru Obasa
Mudashiru Àjàyí Ọbasá jẹ́ agbẹjọ́rò, olóṣèlú ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress ilẹ̀ Nàìjíríà kan. Òun tún ni ó jẹ́ agbẹnusọ fún ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin ìpínlẹ̀ Èkó lọ́wọ́lọ́wọ́.[1]
Right Honourable Mudashiru Obasa | |
---|---|
Speaker of the 8th Lagos State House of Assembly | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 2015 | |
Asíwájú | Adeyemi Ikuforiji |
Constituency | Lagos, Agege Constituency I |
Member of the Lagos State House of Assembly | |
In office 2011–2015 | |
Member of the Lagos State House of Assembly | |
In office 2007–2011 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 11 Oṣù Kọkànlá 1972 |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressive Congress (APC) |
Ẹbí | Married |
Residence | Lagos |
Alma mater | LASU |
Occupation | Legislature |
Profession | Legal Practitioner |
Ibẹ̀rẹ̀ aye rẹ̀
àtúnṣeA bí i ní ilù Agege, ní Ìpínlẹ̀ Èkó ní apa gúsù ìwọ̀ Olorun ilẹ̀ Nàìjíríà. [2]
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ní Ilé-ẹ̀kọ́ St Thomas Acquinas ní Sùúrù-lérè, ṣáájú kí ó tó lọ sí Ilé-ẹ̀kọ́ girama Archbishop Aggey Memorial, ní ìlú Mushin, ní agbègbè Ìlasa-màjà, ní ìpínlẹ̀ Èkó níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gba ìwé ẹ̀rí ìdánwò àpapọ̀ Ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀ (WAEC). [3] Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ìmọ̀òfin ní Ilé-Ẹ̀kọ́ Ìpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 2006. [4]
Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olóṣèlú
àtúnṣeNí ọdún 1999, Mudashiru díje dupò sí ipò àga ijọba ìbílẹ̀ Agege lábẹ́ egbẹ́ òṣèlú Alliance for Democracy bori ó sì borí, léyìí tí ó ṣiṣẹ́ nibẹ̀ láàrín ọdún 1999 sí 2002. [5]
Ẹ̀wẹ̀, ó ran díje dupò sí Ilé ìgbìmọ̀ aṣojúṣòfin ìpínlẹ̀ Èkó ní ẹkùn ìjọba ìbílẹ̀ Agége ní ọdún 2019, tí ó sì tún jáwé olúborí nínú ìdìbò naa, tí ó sì sọ́ di agbẹnusọ́ fun Ilé ìgbìmọ̀ náà ní Ipinlẹ̀ Ẹ̀kó. [6]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Ebhomele, Eromosele. "Meet Obasa, The New Lagos Speaker". The News. The News. http://thenewsnigeria.com.ng/2015/06/meet-obasa-the-new-lagos-speaker/. Retrieved 13 January 2017.
- ↑ Ademola, Jamiu. "The Rise And Rise Of The New Lagos Speaker". Naij. Naij. https://politics.naij.com/456274-the-rise-and-rise-of-the-new-lagos-speaker.html. Retrieved 13 January 2017.
- ↑ Obasa, Mudashiru. "Why I want to come back to House for the fourth time". Econium. http://encomium.ng/why-i-want-to-come-back-to-house-for-the-fourth-time-hon-mudashiru-obasa/. Retrieved 13 January 2017.
- ↑ Ademola, Jamiu. "The Rise And Rise Of The New Lagos Speaker". Naij. https://politics.naij.com/456274-the-rise-and-rise-of-the-new-lagos-speaker.html. Retrieved 13 January 2017.
- ↑ Admin. "Profiles of the new principal officers of Lagos House of Assembly". Emcomium. http://encomium.ng/profiles-of-the-new-principal-officers-of-lagos-house-of-assembly/. Retrieved 13 January 2017.
- ↑ https://punchng.com/breaking-lagos-speaker-obasa-other-win-lagos-house-of-assembly-seats-in-agege/amp/