Mulikat Adeola Akande (tí a bí ní 11 November 1960) jé òtòkùlú olósèlú àti oludije fún ipò senato omo orílè-èdè Nàìjíríà. A dibo yan si ile igbimo asoju láti se asojú Ogbomoso North, South àti orire constituency labé egbé oselu People's Democratic Party(PDP)ni odun 2007, a tun yàn ní odun 2011.[1]

Mulikat Adeola Akande
Senato Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
ConstituencyNorth/South Orire
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí11 Oṣù Kọkànlá 1960 (1960-11-11) (ọmọ ọdún 63)
Kaduna
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople Democratic Party (PDP)
Alma materAhmadu Bello University
University of Lagos

Àárò ayé àti èkó rè

àtúnṣe

A bí Mulikat Adeola ní 11 November, 1960, ní ìpínlè Kaduna, ariwa orílè-èdè Nàìjirià sí idile Alhaji àti Alhaja Akande. O kàwé primari ní ilé-ìwé St. Annes primary School àti ìwé sekondiri ní Queen Amina College ní Kaduna, léyìn náà, o lo si College of Art and Science ní Zaria kí o to dipe o lo sí Yunifásitì ti Ahmadu Bello(ABU) níbí tí o tika nípa ìmò ofin ti ó sì àmì-èye ìmò òfin ni 1982, tí a sì pe sise agbejoro ní odun 1983. O padà lo sí Yunifásitì ìlú Eko láti gba àmì-èye Master of Law rè ní odun 1985.[2]

Òsèlú

àtúnṣe

Ni odun 2007, a dibo yan Mulikat sí ipo ile igbimo asojú labé oselu People's Democratic Party(PDP), a tún dibo yan fún sáà kejì ní odun 2011. Ni odun 2019, o dupò ile ìgbìmò asofin(Senato) sùgbón ó fìdíremi, Abdulfatai Buhari tí o jé omo egbé All Progressive Congress(APC) ni ó wolé sí ipò náà. Mulikat Akande fi egbé oselu PDP sílè ní osu karun odun 2022, ó sì darapo mó egbé Social Democratic Party(SDP), o ti ra fomu ikede idije.[3]

Àwon Ìtókasí

àtúnṣe
  1. "Political Amazon, Mulikat Adeola, Joins The 60th Gang". THISDAYLIVE. 2020-11-15. Retrieved 2022-05-28. 
  2. "Hon. Mulikat Akande Adeola". The Eminent Leaders. 2018-06-06. Archived from the original on 2022-07-03. Retrieved 2022-05-28. 
  3. "Oyo North: Hon Mulikat Akande- Adeola Obtains SDP Nomination Form". National Insight News (in Èdè Latini). 2022-05-05. Retrieved 2022-05-28.