Neveen Dominic
Neveen Dominic je osere, agbere jade, onisowo[1]
Neveen Dominic | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | South Sudan |
Iṣẹ́ | Osere, agbere jade, onisowo ati oninurere |
ati oninurere ti o wa lati Gúúsù Sudan ti on gbe ni ilu Kánádà.[2]
Igbesi aye ara ẹni
àtúnṣeIlu South Sudan ni wwon bi Dominic si. Oni oselu ni baba e[3] iya e si je osere.[4]Ni igba ti o wa ni omo odun medogun ohun ati awon molebi re ko lo si ilu Calgari, Kanada nigba ti ogun waye ni ilu Sudan.[5] Ni osu kakanla odun 2019, ohun ati oko re, omo ilu Nàìjíríà kan ti on gbe ni ilu Kanada[6], bi omo akoko wan.[7]
Iṣẹ
àtúnṣeIle Ise Idanilaraya
àtúnṣeDominic je osere omo South Sudan akoko ti o ko ipa ninu fiimu ilu Naijiria Nollywood.[8] O hun lo se igbejade fiimu jara nollywood ti amo si "It's A Crazy World" o ko ipa ninu ere na. Ni osu keta odun 2019, Eagle Online so wipe on gbero lati pada si enu jara na ni ilu Naijiria.[9] Lehin ti o pada wa, o gba awon osere Nollywood nlanla se ere, awon osere bi Bob-Manuel Udokwu, Amanda Ebeye, Grace Amah, Moyo Lawal, Francis Odega, Tunbosun Aiyedehin, ati Tochi Ejike Asiegbu ninu jara titi Nollywood.[10]
Ohun lo se eto atike olorin ni ose asa ati oge titi New York ni odun 2018, fun Glenroy March[11]
Iṣowo
àtúnṣeOhun ni oluda sile Neveen Dominic Cosmetics, ti o wa ni ilu Calgary, Alberta, Kanada ti ile iise ero won wa ni United States ati Jẹ́mánì.[12] Ni osu kerin odun 2019 o kede pe ohun o ma ta oja ohun ni ilu Naijiria ati Ghánà .[13][14][15]
Ninu itan-akoole ti ara eni ti akori e je "Beauty From The Ashes of War" o so itan aye e gegebi alasasala ti o wa lati South Sudan, o si sope ile ise oge ohun je fun igbiyanju awon obinrin.[16]
Ise Inu rere
àtúnṣeNi asiko ajakale arun COVID-19, o se agbekale bi oti ma fun awon eyan e egberun marun ni ounje. Iwe iroyin Leadership ni o so wipe.
"...mo ti lo si ilu Naijiria fun ise kan, esekese ni mo feran bi awon odo se feran owo sise ni ilu na,ni tori eyi ni mo fe fi bun awon eyan ni owo''[17][18]
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ "Neveen Dominic Cosmetics Debuts the Juba Collection to Cater to Darker-Skinned Beauties". Press Release (New York). March 28, 2017. Archived from the original on October 10, 2020. Retrieved October 10, 2020.
- ↑ Medeme, Ovwe (May 23, 2020). "Neveen Dominic Puts Smiles On Nigerians Faces, To Feed 5,000 People". Independent. Retrieved October 10, 2020.
- ↑ Dallimore, Rebecca (April 2, 2018). "From Refugee to CEO". 360Makeup. Archived from the original on August 5, 2019. Retrieved October 10, 2020.
- ↑ "Meet Neveen Dominic, The Sudanese Filmmaker With A Passion For Nollywood". Independent. February 16, 2019. Retrieved October 10, 2020.
- ↑ Dallimore, Rebecca (April 2, 2018). "From Refugee to CEO". 360Makeup. Archived from the original on August 5, 2019. Retrieved October 10, 2020.
- ↑ EB. "South Sudanese Actress, Neveen Dominic Returns to Premiere ‘It’s A Crazy World’". News of Africa. Archived from the original on March 21, 2019. Retrieved October 10, 2020.
- ↑ Chioma, Ella (November 16, 2019). "Actress, Neveen Dominic welcomes first child in Canada". Kemi Filani News. Retrieved October 10, 2020.
- ↑ Laba, Eseoghene (April 2, 2019). "Neveen Dominic storms Nigeria with new brand of cosmetics". Retrieved October 10, 2020.
- ↑ "Neveen Dominic becomes first Sudanese in Nollywood". The Eagle Online. March 22, 2019. Retrieved October 10, 2020.
- ↑ EB. "South Sudanese Actress, Neveen Dominic Returns to Premiere ‘It’s A Crazy World’". News of Africa. Archived from the original on March 21, 2019. Retrieved October 10, 2020.
- ↑ "Jamaican-born Designer Glenroy March presents latest collection at NY Fashion Week". South Florida Caribbean News. Retrieved October 10, 2020.
- ↑ Medeme, Ovwe (May 23, 2020). "Neveen Dominic Puts Smiles On Nigerians Faces, To Feed 5,000 People". Independent. Retrieved October 10, 2020.
- ↑ Laba, Eseoghene (April 2, 2019). "Neveen Dominic storms Nigeria with new brand of cosmetics". Retrieved October 10, 2020.
- ↑ Prance-Miles, Louise (April 4, 2019). "Sudanese Actress Neveen Dominic Launches Cosmetics Brand in Nigeria". Global Cosmetics News. Retrieved October 10, 2020.
- ↑ "Neveen Dominic storms Nigeria with new brand of cosmetics". Latest Nigerian News. Guardian. April 2, 2019. Retrieved October 10, 2020.
- ↑ "Neveen Dominic becomes first Sudanese in Nollywood". The Eagle Online. March 22, 2019. Retrieved October 10, 2020.
- ↑ Medeme, Ovwe (May 23, 2020). "Neveen Dominic Puts Smiles On Nigerians Faces, To Feed 5,000 People". Independent. Retrieved October 10, 2020.
- ↑ "Neveen Dominic supports Nigerians with cash on Instagram". The Sun. May 23, 2020. Retrieved October 10, 2020.