Nigeria Ministry of Education

Ilé-iṣẹ́ àpapọ̀ ẹ̀kọ́ tí wọ́n máa ń pè ní (Federal Ministry of Education) jẹ́ apá kan ti àwọn ilé-iṣẹ́ àpapọ̀ Naijiria (Federal Ministries of Nigeria) tí ó ń ṣe ìtọ́sọ́nà ètó-ẹ̀kọ́ ní Nàìjíríà. Ó wà ní Block 5A (8th Floor), Federal Secretariat Complex, Shehu Shagari Way, Central Area, P.M.B. 146, Garki, Abuja.

Ààrẹ Muhammadu Buhari yan Adamu Adamu, gbajúgbajà oníròyìn gẹ́gẹ́ bí mínísítà fún ètò ẹ̀kọ́ ní oṣù kọkànlá ọdún 2015.[1]

Iṣẹ́ Wa

àtúnṣe

" Ìpinnu wa ni láti lo ètò-ẹ̀kọ́ gẹ́gẹ́ bí ohun èlò fún ìtèsíwájú ìdàgbàsókè gbogbo àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sí agbára wọn ní kíkún, fún ìgbéga ti orílẹ̀-èdè tí ó lágbára, tiwa-n-tiwa, dọ́gbadọ́gba, tí ó ní ìlọsíwájú, tí a kò pin àti àìbíkítà orílẹ̀-èdè aláṣẹ lábẹ́ Ọlọ́run."[2]

Ilé Iṣẹ́

àtúnṣe

Àwọn isẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú:

  • al policy on education.
  • Collecting and collating data for purposes of educational planning and financing.
  • Maintaining uniform standards of education throughout the country.
  • Controlling the quality of education in the country through the supervisory role of the Inspectorate Services Department within the Ministry.
  • Harmonizing educational policies and procedures of all the states of the federation through the instrumentality of the National Council on Education.
  • Effecting co-operation in educational matters on an international scale.

Ara ilé iṣẹ́ àti àwọn ìtọ́ka sí

àtúnṣe

Parastatal include:

(NBAIS), Kaduna.

  1. "Jubilation at Education Ministry as Adamu takes over". Nigeria. Archived from the original on 2016-03-04. Retrieved 2015-11-14. 
  2. "Home" (in en-US). FEDERAL MINISTRY OF EDUCATION. https://education.gov.ng/.