Oúnjẹ àwọn ará ilẹ̀ Mali

Àdàkọ:Expand French

Jollof rice with vegetables and a boiled egg

Oúnjẹ àwọn ará ilẹ̀ Mali jẹ́ èyí tí ó kó ìrẹsì àti jéró sínú gẹ́gẹ́ bíi àwọn ohun èlò oúnjẹ Mali, àṣà oúnjẹ tó rọ̀gbọ̀kú lórí àwọn irúgbìn.[1][2] Àwọn irúgbìn tí a máa ń pèsè pẹ̀lú àwọn ọbẹ̀ tí a ṣe láti ara àwọn ewébẹ̀ tí ó ṣe é jẹ̀, gẹ́gẹ́ bí spinach, ọ̀dùnkún tàbí baobab, pẹ̀lú ọbẹ̀ tòmátò àti ẹ̀pà. Àwọn oúnjẹ tí a le jẹ pẹ̀lú àwọn ẹran tí a yan gẹ́gẹ́ bíi, ẹran adìẹ, ewúrẹ́, àgùntàn, tàbí ẹran màálù.[1][2]

Oúnjẹ àwọn Malian yàtọ̀ láti ìletò kan sí ìletò mìíràn.[1][2] lára àwọn oúnjẹ ẹkùn ìwọ-oòrùn ilẹ̀ Áfíríkà, àwọn oúnjẹ mìíràn tí wọ́n tún gbajúgbajà ní Mali ni fufu, Dibi, Jollof rice, àti maafe

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 1.2 Velton, p. 30.
  2. 2.0 2.1 2.2 Milet, p. 146.

Bibliography

àtúnṣe

Àdàkọ:Mali topics Àdàkọ:Cuisine of Africa Àdàkọ:Cuisine

Àdàkọ:Authority control