Oṣù Kẹta
Àdàkọ:Kàlẹ́ndà31Ọjọ́Bẹ̀rẹ̀NíỌjọ́ Ẹtì
Osù:| Kínní | Kejì | Kẹta | Kẹrin | Kàrún | Kẹfà | Keje | Kẹjọ | Kẹ̀sán | Kẹ̀wá | Kọkànlá | Kejìlá |
Osù keta (tí àwọn Yorùbá mọ̀ sí Oṣù Ẹrẹ̀nà) jẹ́ oṣù kẹta odun kalenda Gìrẹ́górì àti Julian. Ọjọ́ mokanlelogbon ni o wa ninu Oṣù Ẹrẹ̀nà. Òun ni oṣù kẹ́jì nínú àwọn oṣù méje tí ó ní ọjọ́ mókanlélogún.