Odù Ifá
Odù Ifá jẹ́ ọ̀rọ̀ tàbí ohùn ẹnu Ifá tí ó ní ìtumọ̀ sí ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ sí ìgbésí ayé ẹni tí a ń dífá fún níbàámu pẹ̀lù ìṣẹ̀lẹ̀ ohun tó ti ṣẹ̀ kọjá. Bí a bá ń sọ̀rọ́ nípa àwọn Yorùbá àti ẹ̀sìn ìbílẹ̀ wọn, kò ṣeé ṣe láti kó ọ̀rọ̀ Ifá kéré nínú ẹ̀sìn ìbílẹ̀ wón, pàá pàá jùlọ nínú gbogbo ẹ̀kọ́ tó rọ̀ mọ́ lítíréṣọ̀ alohùn Yorùbá.[1]
Ojú Odù
àtúnṣeOdù Ifá pín sí ojú odù igba ó lé Mẹ́rìndínlọ́gọ́ta (256) nígbà tì àwọn ojú odù wọ̀nyí náà pín sí ọ̀nà mẹ́rìndínlógún tí wọ́n ń sọ̀rọ̀ nípa ìmọ̀ oríṣiríṣi bíi: ìmọ̀ ẹ̀rọ, ìmọ̀ ní bí ayé ṣe wà, ìmọ̀ ìṣègùn, ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Odù ifá àti àwọn ẹ̀sẹ̀ ifá tí wọ́n pín sí tún dá lórí ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa ayé, òdodo, tí ó kún fọ́fọ́ fún àlàyé níoa àyànmọ́ ẹ̀dá òun ọ̀nà ibùlà fún ọmọ adáríhurun. Bákan náà ló tún jẹ́ ìmọ̀ ọ̀nà ìwádìí tí Elédùà yọ̀nda fú Ọ̀rúnmìlà baba Àgbọnìrègún láti fi ṣọmọ aráyé lóore. Àwọn odù Idá wọ̀nyí dà bí ojúpọ̀nà tí ọmọ ènìyàn lè gbà láti rí àyànmọ́ wọn lò ní kíkún, nípa bì àwọn Babaláwo tí wọ́n jẹ́ olùkọ́ ifá bá ṣe ṣàlàyé rẹ̀ níbàámu pẹ̀lú Odù tì ó bá yọ fún ẹni abdífá fún gẹ́gẹ́ bí Ọ̀rúnmìlà tí ó jẹ́ Babaláwo àkọọ́kọ́ ṣe làá kalẹ̀.
Àwọn Odù Ifá
àtúnṣe1. Èjì ogbẹ 2. Ọ̀yẹ̀kú méjì 3. Ọ̀bàrà méjì 4. Òdì méjì 5. Ìwòrì méjì 6. Òfún méjì 7. Ìrosùn méjì 8. Ọ́wọ́rín méjì 9. Ọ̀kànràn méjì 10. Ògúndá méjì 11. Ọ̀sá méjì 12. Òtúúpọ̀n méjì 13.ìká méjì 14. Ìrẹtẹ̀ méjì 15. Ọ̀sẹ́ méjì 16. Òtúá méjì.[2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
1 | |
| |
| |
| |
Èjì ogbè
2 || ||
|| ||
|| ||
|| ||
Ọ̀yẹ̀kú méjì
3 || ||
| |
| |
|| ||
Ìwórì méjì
4 | |
|| ||
|| ||
| |
Òdí méjì
5. | |
| |
|| ||
|| ||
Ìrosùn méjì
6 || ||
|| ||
| |
| |
Ọ̀wọ́nrín méjì
7 | |
|| ||
|| ||
|| ||
Ọ̀bàrà méjì
8 || ||
|| ||
|| ||
| |
Ọ̀kànràn méjì
9 | |
| |
| |
|| ||
Ògúndá méjì
10 || ||
| |
| |
| |
Ọ̀sá méjì
11 || ||
| |
| |
| |
Ìká méjì
12 || ||
|| ||
| |
|| ||
Òtúúrúpọ̀n méjì
13 | |
|| ||
| |
| |
Òtúá méjì
14 | |
| |
|| ||
| |
Ìrẹtẹ̀ méjì
15 | |
|| ||
| |
|| ||
Ọ̀sẹ́ méjì
16 || ||
| |
|| ||
| |
Òfún méjì
ídá
àtúnṣe
- Ikín
- Ọ̀pẹ̀lẹ̀
- Ibò
- Ìrọ́kẹ́
- Ọpọ́n Ifá
- Agere Ifá tàbí Àwo Ifá
- Àpò Ifá
- Ìlù Ifá
- Ọ̀pá ọ̀rẹ̀rẹ̀ tábì Òsùn
Àwọn ìwé ìtọ́ka sí
Àwọn ìwé ìtọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ "Iwe fun Odu Ifa: Ancient Afrikan Sacred Text". Kilombo Restoration & Healing. Archived from the original on 2019-03-07. Retrieved 2019-03-14.
- ↑ "Odu Ifa". Farinade Olokun. 2018-12-30. Retrieved 2019-03-14.
- ↑ ISBN 9780309063
- ↑ ISBN9780309063