Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejì
Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejì tàbí Ogun Agbáyé Kejì jẹ́ ogun tí ó pa gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè agbáyé pọ̀ lẹ́ẹ̀kan-ṣoṣo tí ó bẹ̀ ní àárín ọdún 1939 sí ọdún 1945. Ogun yí jẹ́ èyí tí ó kan gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè agbáyé tí wọ́n jẹ́ alágbára tí wọ́n sì lààmì-laaka. Ọ̀pọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n jagun náà ni a lè pin sí méjì. Àwọn apá kíní ni Òngbèjà nígbà tí àwọn apá kejì jẹ́ Atọ́jà. Iye àwọn tí wọ́n jẹ́ jagun-jagun tí wọ́n kópa nínú ogun yí jẹ́ ọgbàọ́rùn un mílíọ́nù láti àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n jẹ́ ọgbọ̀n lápapọ̀. Àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n jẹ́ oníjà gan an sa ipá wọn nípa lílo gbogbo ọrọ̀-ajé, ìṣúná, ilé-iṣẹ́ jànkàn-jànkàn, ìwádí ìmọ̀ sáyéẹ́nsì tí wọ́n ní láti fi jagun náà, èyí kò jẹ́ kí á mọ̀ nkan ogun àwoọ́n ọmọ ogun nikan ni àwọn orílẹ̀-èdè yí ló láti fi jagun ni tàbí wọ́n lo àwọn nkan mìíràn tí kìí ṣe ti Olohun tí ó jẹ́ ti àwọn ará ìlú lásán. Ogun agbáyé ẹlẹ́kejì yí jẹ́ ọ̀kan gbòógì nínú àwọn ogun tí èmi ati dúkìá ti ṣòfò jùlo lágbàáyé nínú ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ọmọ adáríhurun. Àwọn ológun tí wọ́n sọ ẹ̀mí wọn nu níbi ìjà-àgbà yí jẹ́ mílíọ́nù ọ́nà àádọ́rin àti mílíọ́nù lọ́nà márùndínláàdọ́taọ́sàn án ènìyàn, nígbà tí àwọn tí wọ́n kú jùlọ jẹ́ ará ìlú lásán tí wọn kìí ṣe jagun-jagun. Ohun tí ó fàá tí òkú yí fi pọ̀ tó bẹ̀ẹ́ ni ìwà ìmọ̀ọ́mọ̀-ṣekú pa ọ̀pọ̀ ènìyàn tí àwọn Gẹ̀ẹ́sì ń pe ní jẹ́nósáìtì, nípa ìlànà ìfebipani , pípa àwọn aláìṣẹ̀ àti fífi ajàkálẹ̀ àrùn pani. Wọ́n ṣamúlò àwọn bàlúù dìgbòlùjà nínú ogun àgbáyé yí, ba kan náà ni wọ́n tún lo àwọn àdó olóró tí ó le pa ìlú run, bẹ́ẹ̀ sì ni wọ́n tun lo nuclear weaponsláti jagun lásìkò náà., lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ iwe àdéhùn ati òfin oríṣiríṣi
Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejì | |||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|
Clockwise from top left: Chinese forces in the Battle of Wanjialing, Australian 25-pounder guns during the First Battle of El Alamein, German Stuka dive bombers on the Eastern Front winter 1943–1944, US naval force in the Lingayen Gulf, Wilhelm Keitel signing the German Surrender, Soviet troops in the Battle of Stalingrad | |||||||
| |||||||
Àwọn agbógun tira wọn | |||||||
Àwọn Alájọṣepọ̀ Ìsọ̀kan Sófìẹ̀tì (1941–45)[nb 1] France[nb 2] |
Àwọn Olóòpó Germany Hungary (1941–45) Co-belligerents Puppet states | ||||||
Àwọn apàṣẹ | |||||||
Allied leaders Joseph Stalin |
Axis leaders | ||||||
Òfò àti ìfarapa | |||||||
Military dead: Over 16,000,000 Civilian dead: Over 45,000,000 Total dead: Over 61,000,000 (1937–45) ...further details |
Military dead: Over 8,000,000 Civilian dead: Over 4,000,000 Total dead: Over 12,000,000 (1937–45) ...further details |
Bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀
àtúnṣeA gbọ́ wípé ogun àgbáyé ẹlẹ́kejì yí bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kínní oṣù Kẹsàn an ọdún 1939, nígbà tí orílẹ̀-èdè ilé-iṣẹ́ ológun Nazi ti ilẹ̀ Germany kọlu orílẹ̀-èdè Pólándì tí àjọ ìṣọ̀kan United Kingdom àti orílẹ̀-èdè Faransé náà sì ṣígun kọlu orílẹ̀-èdè Germany lẹ́ni tí ó ń gbèjà orílẹ̀-èdè Pólándì ní ọjọ́ kẹta tí Germany kọlu Pólándì. Níparí ọdún 1939 sí 1941, orílẹ̀-èdè Germany ti ń ṣàkóso lórí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilẹ̀ àti Ìlú ní apá Yúróòpù, lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìfọwọ́bọ̀wé àdéhùn àti òfin oríṣiríṣi. Lẹ́yìn èyí, orílẹ̀-èdè Germany, orílẹ̀-èdè Japan àti orílẹ̀-èdè Italy kórapọ̀ di ọ̀kan tí wọ́n pe orúkọ wọn ní Axis Alliance, nígbà tí àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn náà sì ń dara pọ̀ mọ̀ wọn nígbà tí ó yá. Nínú we àdéhùn tí ọ̀gágun Molotov–Ribbentrop fọwọ́bọ̀ ní oṣù Kẹjọ ọdún 1939, orílẹ̀-èdè Germany àti Soviet Union nígbà náà fọwọ́-sowọ́pọ̀ láti túbọ̀ gba àwọn ilẹ̀ àwọn alámùúlégbè wọn ní Yúróòpù siwájú si.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Akiyesi
àtúnṣe- Footnotes
- ↑ 23 August 1939, the USSR and Germany sign non-aggression pact, secretly dividing Eastern Europe into spheres of influence. USSR armistice with Japan 16 September 1939; invades Poland 17 September 1939; attacks Finland 30 September 1939; forcibly incorporates Baltic States June 1940; takes eastern Romania 4 July 1940. 22 June 1941, USSR is invaded by European Axis; USSR aligns with countries fighting Axis.
- ↑ After the fall of the Third Republic 1940, the de facto government was the Vichy Regime. It conducted pro-Axis policies until November 1942 while remaining formally neutral. The Free French Forces, based out of London, were recognized by all Allies as the official government in September 1944.
Àwọn ìtókasí
àtúnṣe- Adamthwaite, Anthony P (1992). The Making of the Second World War. New York: Routledge. ISBN 0415907160.
- Brody, J Kenneth (1999). The Avoidable War: Pierre Laval and the Politics of Reality, 1935–1936. Transaction Publishers. p. 4. ISBN 0765806223.
- Bullock, A. (1962). Hitler: A Study in Tyranny. Penguin Books. ISBN 0140135642
- Busky, Donald F (2002). Communism in History and Theory: Asia, Africa, and the Americas. Praeger Publishers. ISBN 0275977331.
- Davies, Norman (2008). No Simple Victory: World War II in Europe, 1939–1945. Penguin Group. ISBN 0143114093
- Glantz, David M. (2001). "The Soviet‐German War 1941–45 Myths and Realities: A Survey Essay" (PDF). Archived from the original (PDF) on 2011-06-17. Retrieved 2011-11-12.
- Graham, Helen (2005). The Spanish Civil War: A Very Short Introduction. Oxford University Press, USA. ISBN 0192803778.
- Hsiung, James Chieh (1992). China's Bitter Victory: The War with Japan, 1937–1945. M.E. Sharpe. ISBN 156324246X
- Jowett, Philip S.; Andrew, Stephen (2002). The Japanese Army, 1931–45. Osprey Publishing. ISBN 1841763535
- Kantowicz, Edward R (1999). The rage of nations. Wm. B. Eerdmans Publishing. ISBN 0802844553.
- Kershaw, Ian (2001). Hitler, 1936–1945: Nemesis. W. W. Norton & Company. ISBN 0393322521
- Kitson, Alison (2001). Germany 1858–1990: Hope, Terror, and Revival. Oxford: Oxford University Press. ISBN 9780199134175.
- Mandelbaum, Michael (1988). The Fate of Nations: The Search for National Security in the Nineteenth and Twentieth Centuries. Cambridge University Press. p. 96. ISBN 052135790X.
- Murray, Williamson; Millett, Allan Reed (2001). A War to Be Won: Fighting the Second World War. Harvard University Press. ISBN 0674006801.
- Myers, Ramon; Peattie, Mark (1987). The Japanese Colonial Empire, 1895–1945. Princeton University Press. ISBN 0691102228.
- Preston, Peter (1998). 'Pacific Asia in the global system: an introduction, Wiley-Blackwell. Oxford: Blackwell. p. 104. ISBN 0631202382.
- Record, Jeffery (2005) (PDF). Appeasement Reconsidered: Investigating the Mythology of the 1930s. DIANE Publishing. p. 50. ISBN 1584872160. Archived from the original on 11 April 2010. https://web.archive.org/web/20100411104102/http://www.strategicstudiesinstitute.army.mil/pdffiles/PUB622.pdf. Retrieved 15 November 2009.
- Shaw, Anthony (2000). World War II Day by Day. MBI Publishing Company. ISBN 0760309396.
- Smith, Winston; Steadman, Ralph (2004). All Riot on the Western Front, Volume 3. Last Gasp. ISBN 0867196165.
- Weinberg, Gerhard L. (1995). A World at Arms: A Global History of World War II. Cambridge University Press. ISBN 0521558794
- Zalampas, Michael (1989). Adolf Hitler and the Third Reich in American magazines, 1923–1939. Bowling Green University Popular Press. ISBN 0879724625.