Oluyole FM
Oluyole FM (98.5 MHz) jẹ́ ilé-iṣẹ́ rédíò lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní Ìbàdàn, ti ilé-iṣẹ́ Broadcasting Corporation ti Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ (BCOS). BCOS tún ń ṣiṣẹ́ ìkànnì tẹlifísàn BCOS TV.
City | Ibadan |
---|---|
Frequency | 98.5 MHz |
First air date | 1972 |
Owner | Broadcasting Corporation of Oyo State |
Website | bcos.tv |
Ibùsọ̀ rédíò náà lọ sórí afẹ́fẹ́ ní ọdún 1972 [1] gẹ́gẹ́ bí aṣèrànwọ́ sí iṣẹ́ AM kan àti pé a mọ̀ọ́ sí Rédíò O.Y.O. 2 títí di ọdún 2009, nígbà tí Otunba Christopher Adebayo Alao-Akala, Gómìnà tẹ̀lẹ́rí ti ìpínlẹ̀ yí orúkọ náà padà.[2]
Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Adegbite Adeyanju". GCI Museum. Retrieved 2022-04-09.
- ↑ Ogunyemi, Dele (26 November 2009). "Nigeria: Radio O.Y.O 2 Becomes Oluyole FM". All Africa. Retrieved 27 October 2021.