Omijé
Omijé jẹ́ omí kan tó mọ́ kangá tó.ma ń sun jáde láti inú ibùsun kan tó wà nínú ihò ojú.A lè ṣalábàápàdé omi yí ní ara gbogbo ẹranko afọ́nọlọ́nú tókù yàtọ̀ ewúrẹ́ àti ehoro[1][2]
Kókó iṣẹ́ omijé
àtúnṣe- Fífọ ìdọ̀tí inú ojú,
- Ó ń jẹ́ kí ojú ó lè yí kiri pẹ̀lú ìrọ̀rùn,
- Ó sì ń jẹ́ kí àwọn ọmọ ogun ara ó jí pépé si.
- Ó ma ń jáde látàrí ìmòsí-lára tàbí bí ìṣẹ̀lẹ̀ bá ṣe ṣẹ̀ dí ara. Yálà ní ìlànà ìdùnú ni tàbí ìbànújẹ́. [3] [4]
Ọmọnìyàn nìkan ni ó ma ń fi ìmọ̀sí-lára rẹ̀ hàn pẹ́lú sísun omijé lójú nígbà ayọ tàbí ìbànújẹ́. Omijé tún jẹ́ àmì kan pàtàkì láàrin àwọn ọmọ ènìyàn, pàá pàá jùlọ ẹkún sísun. [4] Sísun ẹkún nígbà tí inú ènìyàn bá bàjé jẹ́ ọ̀nà láti sún àwọn homonu ìdààmú tí ó ti rọ́jọ sí ara jáde pẹ̀lú ẹkún.[5][6]
Àwọn Ìtọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ "Definition of TEAR". www.merriam-webster.com. Retrieved 2019-08-04.
- ↑ "Animals With No Tear Ducts". animals.mom.me. Retrieved 2019-08-04.
- ↑ Farandos, NM; Yetisen, AK; Monteiro, MJ; Lowe, CR; Yun, SH (2014). "Contact Lens Sensors in Ocular Diagnostics". Advanced Healthcare Materials 4 (6): 792–810. doi:10.1002/adhm.201400504. PMID 25400274.
- ↑ 4.0 4.1 "Why do we cry? The scientific reasons behind sobbing". The Independent. 2014-09-18. Retrieved 2019-08-04.
- ↑ "All About Emotional Tears". American Academy of Ophthalmology. 2017-02-28. Retrieved 2019-08-04.
- ↑ Frey, W. H.; DeSota-Johnson, D.; Hoffman, C.; McCall, J. T. (October 1981). "Effect of stimulus on the chemical composition of human tears". American Journal of Ophthalmology 92 (4): 559–567. doi:10.1016/0002-9394(81)90651-6. ISSN 0002-9394. PMID 7294117.