Ewúrẹ́ jẹ́ ẹran ọ̀sìn ilé [1] tí ó jẹ́ olóri kunkun, ẹranko yí a sì máa dùn lọ́bẹ̀.

Ewúrẹ́
Temporal range: 0.01–0 Ma
Neolithic–Recent
A pygmy goat on a stump
Ipò ìdasí
Ọ̀sìn
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ e ]
Ìjọba: Animalia (Àwọn ẹranko)
Ará: Chordata
Ẹgbẹ́: Mammalia (Àwọn afọmúbọ́mọ)
Ìtò: Oníka-dídọ́gba
Ìdílé: Bovidae
Subfamily: Caprinae
Ìbátan: Capra (genus)
Irú:
Irú-ọmọ:
C. a. hircus
Ìfúnlórúkọ mẹ́ta
Capra aegagrus hircus
Synonyms

Capra hircus Linnaeus, 1758
Capra depressa Linnaeus, 1758
Capra mambrica Linnaeus, 1758
Capra reversa Linnaeus, 1758

Orísi ewúrẹ́ tí ó wà

àtúnṣe

Oríṣiríṣi ni eran ewúrẹ́ káàkiri agbáyé, amọ́ irúfẹ́ Oríṣi tí kò bàá jẹ́ takọ tabo ni wọ́n wà. Akọ ewúrẹ́ ni ni a ń pè ní òbúkọ nígbà tí abo ewúrẹ́ jẹ́ ewúrẹ́.



  1. Bradford, Alina (2015-10-21). "Facts About Goats". livescience.com. Retrieved 2020-08-21.