Oníṣe:Agbalagba/Gabriel Okara (1)
Gabriel Okara | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Gabriel Imomotimi Gbaingbain Okara 24 Oṣù Kẹrin 1921 Bomoundi, Niger Delta, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Novelist, poet |
Notable work | The Voice |
Wọ́n bi Gabriel Imomotimi Okara ni ojo Kerinlelogbon osu Kerin odun 1921 (born 24 April 1921). eni ti won bi ni Bumoundi Yenagoa, Bayelsa State. O je akewi ati olukotan omo orile ede Naijria[1] O je okan lara awon akewi igbalode (Modernist poet of Anglophone Africa) ile alawo dudu ti o n so Geesi. Won mo Gabriel latari awon iwe itan , The Voice (1964), ati iwe ewi ti o ko ti o fi gba ami eye, iyen: The Fisherman's Invocation (1978), The Dreamer ati His Vision (2005). Ninu awon iwe itan aroso ati ewi re ni Okara ti ma n fi eko, esin, alo-onitan ati awon ami oniruuru ile alawo dudu han. fun idi eyi, ni won se n pee ni "the Nigerian Negritudist".[2] Gege bi alatunse awon ise re Brenda Marie Osbey, se so, o ni " A le so wipe awon ise olokan-o-jokan paapaa julo ewi akoko ti Gabriel Okara koko ko ni ise litireso orile-ede Naijiiria ati ewi igbalode ile Adulawo ti bere"[3]
Igbesi aye re
àtúnṣeGabriel Imomotimi Gbaingbain Okara, the son of an Ijọ chief,[4] was born in Bomoundi in the Niger Delta in 1921. He was educated at Government College Umuahia, and later at Yaba Higher College. During World War II, he attempted to enlist in the British Royal Air Force but did not complete pilot training, instead he worked for a time for the British Overseas Airway Corporation (later British Airways).[5]
Ni odun 1945, Okara ri ise gege bi atewe fun ile ise itewe ijoba amunisin ile Naijiria. O sise ni ile ise yii titi di igba ti oun naa fi bere si ni kowe jade. O koko sogbufo ewi kan lati ede Ijaw si ede Geesi, ti o si ko iwe fun ile ise iroyin asoro-magbesi ijoba . O keko nipa imo igbohun-safefe ni ile eko agba ti Northwestern University ni odun 1949 saaju ija ogun abele Nigerian Civil War to be sile ni odun(1967–70). O si tun sise gege bi Information Officer fun apa Ariwa ijoba Naijiria (Eastern Nigerian Government Service), ati onkowe Chinua Achebe, Okara tun je asoju fun Biafra laarin odun1969.[6] Lati 1972 si 1980, O je adari fun ile ise atewe ipinle Rivers State to wa ni Port Harcourt.[7]
Awon iwe re
àtúnṣeReferences
àtúnṣe- ↑ Laurence, Margaret; Stovel, Nora Foster (2001). Long Drums & Cannons: Nigerian Dramatists and Novelists, 1952-1966. University of Alberta. pp. 171–. ISBN 978-0-88864-332-2. https://books.google.com/books?id=QxYr-RW-yF8C&pg=PA171. Retrieved 8 May 2011.
- ↑ Sumaila Umaisha, "Gabriel Imomotimi Gbaingbain Okara: The Poet of the Nun River — interview", African Writing, No. 6.
- ↑ Brenda Marie Osbey, Introduction, Gabriel Okara: Collected Poems, University of Nebraska Press, 2016.
- ↑ "Gabriel Okara," in Hans M. Zell, Carol Bundy, Virginia Coulon, A New Reader's Guide to African Literature, Heinemann Educational Books, 1983; pp. 445–447.
- ↑ James M. Manheim, "Okara, Gabriel 1921–", Contemporary Black Biography . Encyclopedia.com.
- ↑ "Gabriel Okara (Gabriel Inomotimi Gbaingbain Okara) Biography", Jrank.org.
- ↑ "Gabriel Okara", Encyclopædia Britannica.
[[Ẹ̀ka:Àwọn ọjọ́ìbí ní 1921]] [[Ẹ̀ka:Àwọn ènìyàn alààyè]]