Ada Ameh jẹ́ òṣèré ará ìlú Nàìjíríà kan tí ó ti lò ju ọdún ogún lọ ní ilé-iṣẹ fíìmù ti Nàìjíríà àti pé ó ṣe àkíyèsí jùlọ fún ipa rẹ̀ bi Anita ni fiimu 1996 tí àkọlé rẹ̀jẹ́ “ Domitilla” àti bi Emu Johnson nínú eré aláàmì-ẹ̀ye ti àkọlé rẹ jẹ́ Johnsons . Ameh nínu The Johnsons ṣe ìfihàn lẹ́gbẹ̀ẹ́ àwọn òṣèré Nollywood mìíràn bii Charles Inojie, Chinedu Ikedieze & Olumide Oworu .[2][3][4]

Ada Ameh
Ọjọ́ìbíAda Ameh
May 15
Ajegunle, Lagos State
Aláìsí17 July 2022[1]
Warri, Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́
  • Actress
  • Comedian
Ìgbà iṣẹ́1995-Present
Àwọn ọmọ1

Ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀ àti ẹ̀kọ́

àtúnṣe

Ameh, bótilẹ̀jépé o jẹ́ abínibí ti Idoma ni Ipinle Benue, a bí tí o si dàgbà nìi Ajegunle ni Ipinle Eko, apá ìhà ìwọ-oòrùn gúúsù ìwọ-oòrùn ti Nàìjíríà tí ó borí púpọ̀ nípasẹ̀ àwọn ènìyàn tí n sọ èdè Yorùbá ti Nigeria . Ameh gba ẹ̀kọ́ ilé-ìwé alàkọ̀bẹ̀rẹ̀ àti ilé-ìwé giga ni ipinlẹ Eko ṣùgbọ́n óó parí ilé-ìwé ọjọ́-orí 14.[5]

Iṣẹ́

àtúnṣe

Ameh Ní ọdún 1995 ní ìfọwọ́sí apákan ti ilé-iṣẹ́ fíìmù ti Nollywood àti gba ipò fíìmù àkọ́kọ́ rẹ ní ọdún 1996 níbití ó ti kópa bí Anita ní fiimu “Domitila” Fíìmù kan tí ó di iṣẹ́ àṣeyọrí . Fíìmù náà ṣe àgbékalè àti ṣe ìtọ́sọ́nà nípasẹ̀ Zeb Ejiro . Ameh tún ṣe ìfihàn nínu jara TV ti Nàìjíríà tí àkọ́lé rè jẹ́ the Johnsons èyítí o tun di iṣẹ́ àṣeyọrí tí ó gba àwọn àmì-ẹri .[6][7]

Igbésí ayé ara ẹni

àtúnṣe

Ameh Ní ọmọ obìnrin kan tí ó bí ní gbà tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rìnlá. Ameh jẹ ẹniti ó ń sọ èdè míràn ati èdè abinibi agbègbè rẹ̀ ní èdè Idoma, Gẹẹsi, Yoruba ńsọ ọ́pọ́ èdè àtioèdèNí ọdún 2017 wón gbé àkọle olórí fún Ameh ni Ipinle Benue[8][9]

Filmography tí ayàn

àtúnṣe
  • Domitila
  • Aki na Ukwa (pẹ̀lú Osita Iheme & Chinedu Ikedieze)[10]
  • Phone Swap (pẹ̀lú Wale Ojo, Chika Okpala, Nse Ikpe-Etim & Joke Silva)[11]
  • Blood Money' '[12]
  • Atlas Oloture
  • Our Husband
  • King Of Shitta
  • Ghana Must Go[13]
  • A Million Baby[14]
  • One Good Turn
  • Double Trouble

Eré Tẹlifiṣọ̀nù

àtúnṣe

Àkópó Ìtọ́kasí

àtúnṣe