Ìdíje Open Tẹ́nìs Amẹ́ríkà tabi United States Open Tennis Championships, bakanna bi US Open, Open Amerika tabi Flushing Meadows, je idije tenis ori papa lile to je atunse odeoni ikan ninu awon idije tenis to pe julo lagbaye, eyun U.S. National Championship (Idije Omoorile-ede Amerika) ti fun awon okunrin enikan bere ni 1881.

Open Amẹ́ríkà
US Open
Fáìlì:US Open.svg
Official website
IbùdóNew York City - Queens
Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan United States
PápáUSTA Billie Jean King National Tennis Center
Orí pápáGrass - outdoors (1881–1974)
Clay - outdoors (1975–1977)
DecoTurf - outdoors (1978–present)
Men's draw128S / 128Q / 64D
Women's draw128S / 96Q / 64D
Ẹ̀bùn owóUS$22,063,000 (2011)
Grand Slam
Current
2012 US Open (tennis)
Open America(US) ti ọdún 2019