Ìjalèlókun: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
 
Ìlà 2:
[[Fáìlì:Jacquesdesores.jpg|right|thumb|250x250px| Ajalèlókun Faransé Jacques de Sores jẹ́rùkó tí ó sì ń jó Havana ní ọdún 1555]]
'''Ìjalèlókun '''jẹ́ ìwa olèjíjà tàbí ìwà ọ̀daràn ní okun. Àwọn tí ó ń lọ́wọ́sí ìwà Ìjalèlókun ni wọ́n ń pè ní àwọn ajalèlókun. Àkosílẹ̀ àpẹẹrẹ ìjalèlókun  tí ó pẹ́jù ṣẹlẹ̀ ní bíi Orundún mẹ́rìnlá sẹ́yìn, nígbà tí àwọn ẹgbẹ́ ajalè lórí òkun dojú kọ ọkọ̀ ojú omi ti Aegean àti Mediterranean tí kò digun. Àwọn ònà tóóró tí ó ń jẹ́ kí wọn mọ ònà ibi tí ọkọ̀ ojú omi gbà ń fa ààyè fún ìjalèlókun,<ref>{{Àdàkọ:Cite book|last1=Pennell|first1=C. R.|chapter=The Geography of Piracy: Northern Morocco in the Mod-Nineteenth Century|editor1-last=Pennell|editor1-first=C. R.|title=Bandits at Sea: A Pirates Reader|url=https://books.google.com/books?id=uB7ODGowJ3AC|publisher=NYU Press|publication-date=2001|page=56|isbn=9780814766781|accessdate=2015-02-18|quote=Sea raiders [...] were most active where the maritime environment gave them most opportunity. Narrow straits which funneled shipping into places where [[ambush]] was easy, and escape less chancy, called the pirates into certain areas.}}</ref>  tí ó tún ń fa ààfàní fún idigun ja ọkọ̀ ojú omi àti oníṣowò ojú omi.
<span class="cx-segment" data-segmentid="46"></span>
 
==Àwọn ìtọ́kasí ==
{{Reflist|30em}}
 
[[Ẹ̀ka:Àyọkà kúkurú]]