Emmanuel Ifeajuna: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Ìmúkúrò àtúnyẹ̀wò 540163 ti T Cells (ọ̀rọ̀)
Ìlà 3:
Ọmọ bibi ilu Onitsha ni ẹya ibo lati orilẹ-ede Naijiria ni i ṣe, o si kẹkọ gboye ninu imoijinlẹ sayẹnsi lati ile-iwe giga ti Yunifasiti Ibadan. O dara pọ mo oṣelu, lẹyin eyi ni o tun gba iṣẹ ologun. O ko ipa pataki ninu ifipa gba ijọba lowo oloselu ti o waye ni orilẹ-ede Naijiria ni ọdun 1966.
 
== IgbeÌgbé AyeAyé atiàti iṣẹiṣẹ́ ==
 
==== EreEré idarayaìdárayá ifoìfò fifofífò ====
Ọmọ bibibíbí iluìlú [[Onitsha]]<ref name="MS1">Siollun, Max (2005-10-30). "The Inside Story Of Nigeria’s First Military Coup (I)". ''Nigeria Matters''. Retrieved on 2014-07-13.</ref> ni, oó lọ si IleIlé-iweìwé Girama Dennis Memorial ni ilu abinibi rẹ o si fi awọn abuda ti yoo sọ ipa ti igbesi aye rẹ tọ han nigba naa. OlukọOlùkọ́ ereeré idarayaìdárayá ni ile-iwe girama rẹ ni o kọ ọ ni ere idaraya ifo fifo<ref>Oliver, Brian (2014-07-13). "Emmanuel Ifeajuna: Commonwealth Games gold to facing a firing squad". ''The Guardian''. Retrieved 2014-07-13.</ref>. Bakanna ni o wa lara awon ti o fi ehonu han eleyi ti o mu ki won gbe ile-ẹkọ giga re fun saa ẹkọ kan. O jade ile-iwe girama ni ọdun 1951<ref>Onyema, Henry (2013-10-23). "EMMANUEL IFEAJUNA – The Man Called Emma Vancouver". Naija Stories. Retrieved 2014-07-13.</ref> Ile-iwe Girama ti Ilesa naa le ka a kun awon akeko ti o jade nibe, biotilejepe awon ariyanjiyan kan jeyo ninu iroyin yi, sugbon o daju wipe o ṣe ile ẹkọ fun saa akoko oorun nigba kan ri nibe.<ref>Major Emmanuel Ifeajuna Archived 14 July 2014 at the Wayback Machine. Ilesa Grammar School. Retrieved 2014-07-13.</ref>
 
== Àwọn ìtọ́kasí ==