Tolulope Arotile: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
#WWH
 
Ìlà 1:
'''Tolúlọpẹ́ Olúwatóyìn Sarah Arótilé''' tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtalélógún oṣù Kejìlá ọdún 1996)5 tí ó ṣaláìsí ní ọjọ́ọ́ Kẹrìnlá oṣù Keje ọdún 2020. Tolúlọpẹ́ jẹ́ olùkọ́ [[ọkọ̀ òfurufú]] àwọn jagunjagun ní ilé iṣẹ́ ológun òfurufú, ó sì tún jẹ́ [[obìnrin]] akọ́kọ́ tí yóò jẹ́ jagunjagun tí ó ń fi ọkọ̀ ìjà òfurufú jagun ní orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]]. <ref> {{cite web|title=Nigeria mourns first ever female helicopter combat pilot: Tolulope Arotile|website=Africanews|date=2020-07-15|url=https://www.africanews.com/2020/07/15/nigeria-mourns-first-ever-female-helicopter-combat-pilot-tolulope-arotile/|ref={{sfnref | Africanews | 2020}}|access-date=2021-06-13}}
</ref>
Tolúlọpẹ́ jẹ́ ọmọ bíbí arákùnrin àti abilélkọ Akíntúndé Arótilé tí wọ́n ń gbé ní ìlú [[Kàdúná]] . ti oO si lo si ile-iwe alakọbẹrẹ Airforce ati Secondary ṣaaju ki o to lọ si aabo Ile Eko Oro Abo [[Nigerian Defence Academy|Naijiria]] (NDA) fun ede tetiary education nibi ti o ti ka Iṣiro.
 
== Ìgbà èwe rẹ̀ ==