Princess Osayomwanbor Peters jẹ́ akọrin ìhìnrere àti òṣèré ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1]

Princess Peters
Osayomwanbor
Peters in 2020
Peters in 2020
Background information
Ọjọ́ìbí1 Oṣù Kẹ̀wá 1986 (1986-10-01) (ọmọ ọdún 38)
Edo State, Nigeria
Irú oringospel, contemporary gospel, worship
Occupation(s)Singer, Songwriter, Actress, Producer
InstrumentsVocals
Years active2004–present
LabelsLightworld Productions
Websiteprincesspeters.com

Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Peters sí ìlú Benin ní Ìpínlẹ̀ Ẹdó. Òun ní ọmọ kẹjọ nínú ọmọ mẹ́wàá tí àwọn òbí rẹ bí.[2][3] Ó gbà NCE rẹ̀ nínú ìmò Biology àti Integrated Science láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí College of Education ní Benin ní ọdún 2006. Ó tẹ̀ síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Benson Idahosa University láti gboyè nínú ìmò Mass Communication.[4]

Iṣẹ́

àtúnṣe

Peters bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ nígbà tí ó wà ní ọmọdé. Ó wá ní ẹgbẹ́ akọrin tí àwọn ọmọdé ní ilé ìjọsìn tí àwọn òbí rẹ̀. Ó tí gbé oríṣiríṣi àwọn orin jáde bíi Kpomwen Ijesu,Urhuese, Ose, àti Ogboviosa.[5][6] Ó ṣe eré àkọ́kọ́ rẹ̀ ní ọdún 2014. Òun ni olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ Lifted Hands Initiative àti Princess Peters Foundation èyí tí ó gbé kalẹ̀ láti le máa fi ṣe iranlọwọ fún àwọn aláìní.[7]

Àṣàyàn àwọn eré tí ó tí ṣe

àtúnṣe
  • What's Within (2014)
  • Destiny Gate
  • Home in Exile
  • Girls Are Not Smiling (2017)
  • About Tomorrow
  • Adesuwa
  • ATM
  • Desperate Love
  • Singles Clinik

Àmì ẹ̀yẹ

àtúnṣe
Ọdún Ayẹyẹ Èbùn Èsì
2020 Nigeria Charisma Award Rokkie of the year Gbàá [8]
2020 Maranatha Awards USA Best Collaboration Song 2020 Yàán [9]
2020 Maranatha Awards USA Best Inspirational Worship Leader Yàán [10]
2020 Maranatha Awards USA Masterpiece Gospel Music Video Yàán [11]
2016 Best Of Nollywood Awards Most promising actress of the year Yàán [12]

Àwọn Ìtọ́kàsi

àtúnṣe
  1. "Princess Peters hints fans on new Studio Album". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-07-11. Retrieved 2020-07-12. 
  2. "Princess Peters aims for the sky". February 27, 2019. 
  3. https://www.thisdaylive.com/index.php/2020/05/07/princess-peters-brands-need-to-start-considering-gospelaartists-for-ambassadorial-roles/)
  4. "Princess Peters aims for the sky". February 27, 2019. 
  5. "Nigerian Actress Princess Peters Releases Official Music Video Of ‘Aigbovbiosa' |Nigerian News". June 14, 2019. Archived from the original on November 27, 2020. Retrieved November 19, 2020. 
  6. "URHUESE - Princess Peters ft Godwin Idios" – via www.gospelnaija.com. 
  7. "Nollywood actress, Princess Peters to empower youths, widows". July 31, 2019. Archived from the original on May 22, 2021. Retrieved November 19, 2020. 
  8. "Fast-rising singer, Princess Peters, bags award - The Nation Nigeria". Latest Nigeria News, Nigerian Newspapers, Politics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-05-06. Retrieved 2020-10-08. 
  9. Published. "Princess Peters nominated for Maranatha Awards in US". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-10-08. 
  10. "Popular Nigerian Gospel singer, Princess Peters nominated for Maranatha Award USA - Kemi Filani News". kemifilani.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-07-14. Retrieved 2020-10-08. 
  11. Latestnigeriannews. "Princess Peters nominated for Maranatha Awards in US". Latest Nigerian News (in English). Retrieved 2020-10-08. 
  12. BellaNaija.com (2016-11-25). "Adesua Etomi, Wale Ojo, Enyinna Nwigwe & More Nominated for the 2016 BON Awards". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-10-08.