Rótìmí Akérédolú
His Excellency Olúwarótìmí Ọdúnayọ̀ Akérédolú | |
---|---|
Governor of Ondo State | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 24 February 2017 | |
Asíwájú | Olusegun Mimiko |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Oluwarotimi Odunayo Akeredolu 21 Oṣù Keje 1956 Owo, Ondo State |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Betty Anyanwu-Akeredolu |
Alma mater | Obafemi Awolowo University |
Occupation | Politician Lawyer |
Website | aketi.org |
Olúwarótìmí Ọdúnayọ̀ Akérédolú, SAN, or Rótìmí Akérédolú, ní wọ́n bí ní Ọjọ́ kọkànlélógún oṣù keje ọdún 1956 (21st July 1956) jẹ́ òṣèlú, agbẹjọ́rọ̀ àti Gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó lọ́wọ́lọ́wọ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà , [1] Ó jẹ́ amòfin-àgbà SAN tí ó ti joyè alága àwọn amọ̀fin Nigerian Bar Association lọ́dún 2008.[2] Kí ó tó di Gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó, ó jẹ́ ọ̀kan lára olùdásílẹ̀ ilé iṣẹ́ amọ̀fin, Olujinmi & Akeredolu,[3] a Law Firm he co-founded with Chief Akin Olujinmi, a former Attorney General and Minister for Justice in Nigeria. Ó gbapò ìṣèjọba ìpínlẹ̀ Oǹdó lọ́wọ́ Gómìnà-àná ti ìpínlẹ̀ náà, Olúṣẹ́gun Mimiko
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Breaking Ondo decides Inec officially declares Rotimi Akeredolu Governor elect". www.premiumtimesng.com. Retrieved 27 November 2016.
- ↑ "Nigerian Bar". www.nigerianbar.org. Archived from the original on 8 October 2011. Retrieved 27 November 2016.
- ↑ "Olujinmi Akeredolu". Retrieved 27 November 2016.