Rauf Olaniyan
Olóṣèlú
Rauf Aderemi Olaniyan (tí wọ́n bí ní 25 February 1960) jẹ́ olóṣèlú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, onímọ̀ ẹ̀rọ̀ tó ń kọ́lé, àti àgbẹ̀.
Rauf Olaniyan | |
---|---|
Deputy governor of Oyo State | |
In office 29 May 2019 – 18 July 2022 | |
Gómìnà | Seyi Makinde |
Arọ́pò | Bayo Lawal |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Rauf Aderemi Olaniyan 25 Oṣù Kejì 1960 |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Bolanle Olaniyan |
Alma mater | University of Nigeria |
Occupation |
|
[1][2] Ó jẹ oyè igbá-kejì gómìnà ti ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ láti ọdún 2019 sí ọdún 2022, kí wọ́n tó yọ ọ́ nítorí àṣemáṣe àti àwọn ẹ̀sùn lóríṣiríṣi tí wọ́n kà si lẹ́sẹ̀.[3][4][5][6]Wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí igbá-kejì gómìnàIgbakeji gomina ni won yan an gege bi oludije Seyi Makinde ninu idibo gomina ipinle Oyo lodun 2019 . O maa n sọrọ ni ipo gomina lori awọn ọrọ ti o waye laarin ipinle fun anfani orilẹ-ede.
- ↑ "10 amazing facts about Engineer Rauf Olaniyan". NationalInsightNews.com. Retrieved 19 February 2021.
- ↑ "Rauf Olaniyan Deputy Governor of Our State". TodayNG. Retrieved 25 February 2021.
- ↑ "Oyo Assembly removes deputy gov". Punch Newspapers. 18 July 2022. https://punchng.com/oyo-assembly-removes-deputy-gov/.
- ↑ "How SARS operatives brutalised me, by Oyo Deputy Governor". TheNationOnlineNG. 20 October 2020. Retrieved 25 February 2021.
- ↑ "Oyo govt. committed to independent judiciary–Olaniyan". NNN.NG. 7 October 2019. Retrieved 25 February 2021.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Makinde Not Fair To Me, Oyo Deputy Governor, Olaniyan Cries Out". SaharaReporters.com. Retrieved 25 February 2021.