Oluseyi Makinde

Olóṣèlú
(Àtúnjúwe láti Seyi Makinde)

Olusèyí Abiọ́dún Mákindé ni a bí ní ọjọ́ Karùndínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá, ọdún 1967 (25 December 1967). Ó jẹ́ oníṣòwò, olóṣèlú àti ọlọ́rẹ àtinúwá Ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni Gómìnà tí ó ń bẹ lórí àléfà lọ́wọ́lọ́wọ́ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́[1] ní apá Ìwọ̀-Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà.[2] Wọ́n dìbò yàn-án ní Ọdún 2019 lábé àsíá ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party (PDP) Ó jẹ́ onímọ̀-ẹ̀rọ àti onímọ̀ nípa ìwọ̀n epo àti afẹ́fẹ́ gáàsì (fluid and Gas Metering).[3]

Oluseyi Abiodun Makinde
File:Oluseyi Makinde.png
Present Governor of Oyo State in His Office
Gomina Ipinle Oyo
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
May 29, 2019
AsíwájúAbiola Ajimobi
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Oluwaseyi Abiodun Makinde

Oṣù Kejìlá 25, 1967 (1967-12-25) (ọmọ ọdún 54)
Ibadan
AráàlúNigerian
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party
(Àwọn) olólùfẹ́Tamunominini Makinde
Àwọn ọmọ3
ÌyáAbigail Makinde[citation needed]
BàbáOlatubosun Makinde[citation needed]
EducationUniversity of Lagos
OccupationPolitician, Engineer
Known forGroup Managing Director of Makon Group Limited

Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe