Ray Charles
Ray Charles (September 23, 1930 – June 10, 2004) je olorin omo orilee-ede Amerika. Charles je asiwaju ninu iru orin soul larin awon odun 1950 nipa sisadalu rhythm & blues, gospel, ati blues sinu awon awo orin re ni Atlantic Records.[1][2]
Ray Charles | |
---|---|
Ray Charles in 1990 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Ray Charles Robinson |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Leesburg, Georgia, U.S. |
Irú orin | R&B, soul, rock and roll, blues, jazz, country, pop, gospel |
Occupation(s) | Singer-songwriter, musician, arranger, bandleader |
Instruments | Vocals, piano, keyboards, alto saxophone, trombone |
Years active | 1947–2004 |
Labels | Atlantic, ABC, Warner Bros., Swingtime, Concord |
Associated acts | The Raelettes, Quincy Jones, Betty Carter, Marvin Gaye, James Brown, Little Richard |
Website | Official website |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Unterberger, Richie. Biography: Ray Charles. Allmusic. Retrieved on 2009-11-26.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedVH1