Richard Phillips (oníṣòwò ojú omi)

Richard Phillips (bíi Ọjó kẹrindínlógún Oṣù karún Ọdún 1955[2]) jẹ́ oníṣòwò ojú omí ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà tí ó jẹ́ ògá ọkọ̀ MV Maersk Alabama nígbà tí àwọn  ajalèlókunSomalia fẹ́ já ọkọ̀ náà gbà ní Oṣù kẹrin Ọdún 2009.

Ọ̀gá ọkọ̀
Richard Phillips
Phillips ń sọ̀rọ̀ pẹ̀lú Ààrẹ Barack ObamaIlé fúnfún ní Oṣù karún Ọdún 2009.[1]
Ọjọ́ìbí16 Oṣù Kàrún 1955 (1955-05-16) (ọmọ ọdún 69)
Winchester, Massachusetts, U.S.
Orílẹ̀-èdèọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà
Iṣẹ́oníṣòwò ojú omi, akọ̀wé
Gbajúmọ̀ fúnọ̀gá ọkọ̀ ti MV Maersk Alabama nígbà Ìfipá Gba Maersk Alabama ní Ọdún 2009

Ìgbà èwe àti ẹ̀kọ́

àtúnṣe

Wọ́n bí Phillips ní Massachusetts,[3] ó kàwé jade ní ilé ìwé Winchester High School ní Ọdún 1973.[4]Phillips wọ ilé ìwé gíga University of Massachusetts Amherst, ó sì pinu lati kà òfin gbogboògbò ṣùgbón wọ́n gbe sí Massachusetts Maritime Academy, níbi tí ó ti kàwé jade ni Ọdún 1979.[5] Nígbà tó ń kàwé lọ́wọ́ ó ń ṣisẹ́ awakọ̀ ní Boston.[6]

Àwọn ìtọkasí

àtúnṣe