Sàmóà Amẹ́ríkà

(Àtúnjúwe láti Sàmóà ti Amẹ́ríkà)

Orílẹ̀-èdè kan ni ó ń jẹ́ American Samoa. Ètò ìkànìyàn 1995 sọ pé àwọn ènìyàn ibè jẹ́ ẹgbẹ̀rún lọ́nà ojójì ó lé mẹ́ta (43, 000). Èdè Gèésì ni èdè tí wọ́n fi ń ṣe ìjọba. Ìdá àádọ́rùn-ún nínú ọgọ́rùn-ún àwọn ènìyàn tí ó ń gbé ibẹ̀ ni ó ń sọ Samoan. Àwọn kan tún ń sọ Tongan àti Tokelau

American Samoa

Amerika Sāmoa / Sāmoa Amelika
Motto: "Samoa, Muamua Le Atua"  (Samoan)
"Samoa, Let God Be First"
Location of Sàmóà Amẹ́ríkà
OlùìlúPago Pago1 (de facto), Fagatogo (seat of government)
Ìlú tótóbijùlọTafuna
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaEnglish,
Samoan
Orúkọ aráàlúAmerican Samoan
ÌjọbaUnincorporated territory of the United States
• President
Barack Obama (D)
• Governor
Togiola Tulafono (D)
Ipulasi Aitofele Sunia (D)
AṣòfinFono
Senate
House of Representatives
Unincorporated territory of the United States
1899

1900

1904
• Annexation of Swains Island

1925
Ìtóbi
• Total
199 km2 (77 sq mi) (212th)
• Omi (%)
0
Alábùgbé
• 2010 census
55,519 (208th)
• Ìdìmọ́ra
326/km2 (844.3/sq mi) (35th)
GDP (PPP)2007 estimate
• Total
$537 million (187)
• Per capita
$8,000 (98)
OwónínáUS dollar (USD)
Ibi àkókòUTC-11 (Samoa Standard Time (SST))
Àmì tẹlifóònù+1-684
Internet TLD.as
  1. Fagatogo is identified as the seat of government.
Map of American Samoa.