Sístẹ̀mù Òrùn

Ọ̀nà ètò tòòrùn (solar system) je oorun ati awon ohun oke-orun ti o n yi ka.

Awon eyi pataki ninu ona eto toorun (ki se bi won se tobi si, lati apaosi de apaotun): Pluto, Neptunu, Uranosi, Satonu, Jupita, agbegbe awon irawo, Oorun, Mekiuri, Fenos, Ilẹ̀-ayé & Osupa, and Maasi. Atun ri Okutaina orun kan ni apa osi


ItokasiÀtúnṣe