Salamatu Hussaini Suleiman

Salamatu Hussaini Suleiman jẹ́ agbejọ́rọ̀ tí ó sì jẹ komísọ́nà lórí ọ̀rọ̀ òṣèlú, àlàáfíà àti àbò fún ẹgbẹ́ ECOWAS.[1] Ní oṣù kejìlá ọdún 2008, wọ́n fi jẹ mínísítà lórí ọ̀rọ̀ obìnrin àti ìdàgbàsókè ìlú.[2][3]

Salamatu Hussaini Suleiman
Ecowas Commissioner for Political Affairs, Peace and Security
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
January 2012
Minister of Women Affairs
In office
December 2008 – March 2010
AsíwájúSaudatu Bungudu
Arọ́pòJosephine Anenih
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíArgungu, Kebbi State, Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
EducationLLB, Ahmadu Bello University, Zaria, Master's degree in Law, London School of Economics and Political Science
ProfessionLawyer

Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ àtúnṣe

Wọ́n bí Salamatu Hussaini Suleiman sí ìlú Argungun ní ìpínlẹ̀ Kebbi. Bàbá rẹ̀ jẹ́ adájọ́, ìyá rẹ sí wá láti ìdílé ọba ní Gwada. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Queens College ni Èkó. Ó tẹ̀ síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Ahmadu Bello Universityìpínlẹ̀ Zaria, ó sì gboyè nínú ìmò òfin.

Iṣẹ́ àtúnṣe

Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ pẹ̀lú Ministry of Justice ní ìpínlẹ̀ Sókótó. Lẹ́hìnńà ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ilé ìfowópámọ́ Continental Merchant Bank ní ìlú Èkó fún ọdún méje. Ó siṣẹ́ pẹ̀lú NAL Merchant Bank fún ìgbà díè kí ó tó lọ sí Ilé iṣẹ́ Aluminium Smelter Company níbi tí ó ń tí ṣe onímòràn òfin fún wọn. Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tẹ́lẹ̀, Umaru Yar'Adua fi Suleiman jẹ mínísítà lórí ọ̀rọ̀ àwọn obìnrin ní oṣù kejìlá ọdún 2008.[4][5]

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. KPOGNON, Paul D. "CEDEAO". news.ecowas.int. Archived from the original on 2018-09-26. Retrieved 2017-12-20. 
  2. LAMBERT TYEM (May 11, 2009). "I’m not a politician, but a technocrat –Salamatu Suleiman, Women Affairs Minister". Archived from the original on July 18, 2009. Retrieved 2009-12-26.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. Daniel Idonor (17 March 2010). "Jonathan Sacks Ministers". Vanguard. Retrieved 2010-04-14. 
  4. Anza Philips, Abuja Bureau (24 December 2008). "The Coming of New Helmsmen". Newswatch. Retrieved 2009-12-26. 
  5. Damilola Oyedele (16 September 2009). "Minister Decries Low Women Participation in Politics". This Day. Retrieved 2009-12-26.