Seerat-e Mustafa
Seerat-e Mustafa (Urdu: سیرت مصطفیؐ) jẹ́ ìtàn alásọ̀tẹ́lè ti sẹ́ńtúrì ogún tí wọ́n kọ ní èdè Urdu, láti ọwọ́ Idris Kandhlawi. Ìpìlẹ̀ rẹ̀ dá lórí àwọn òkòdoro ìtà, èyí tí wọ́n gbé kalẹ̀ ní ọ̀nà ìgbàlódé, pẹ̀lú orísun Lárúbáwá,[1] ìtàn náà jẹ́ ìdáhùn sí Sirat al-Nabi láti ọwọ́ Shibli Nomani,[2] tó sọ nípa àwọn tíọ́rí ti Syed Ahmad Khan àti Shibli Nomani gbé kalẹ̀.[3] Ó gbajúmọ̀ fún ìlọ́wọ́sí òyè ìgbàlóde,[4] ìwé náà si sọ sí àwọn ìtakò tó wáyé látàrí ìtàn àwọn àsọtẹ́lẹ̀ náà.[5]
Colourful image English cover | |
Olùkọ̀wé | Idris Kandhlawi |
---|---|
Àkọlé àkọ́kọ́ | سیرت مصطفی |
Country | Pakistan |
Language | Urdu |
Subject | Sīrah |
Genre | Classic |
Published | 1941 (As per the İslâm Ansiklopedisi) |
Published in English | 2011 |
Media type | |
ISBN | Àdàkọ:ISBNT English |
297.09 |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Bhat, Javid Ahmed (2022). "Overview of Prominent Sīrah Writings of Modern Period: Modern Sirah Writings". Karachi Islamicus 2 (2): 30. doi:10.58575/ki.v2i2.29. ISSN 2790-6558. https://karachiislamicus.com/index.php/ki/article/view/29.
- ↑ Dockrat, Ashraf (2017). An Overview of the Sirah Literature. Sirah Convention. Linbro Park, Sandton, Gauteng: Jamia Uloom-ul-Islamia; Cordoba Academy. p. 21. Archived from the original on 5 January 2023. Retrieved 26 August 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Àdàkọ:Cite thesis
- ↑ Ahmad, Munir; Khan, Hafiz Waqas; Khattak, Hafeez Ullah (2022). "Sheikh Muhammad Idris Al-Kandhlawi, and his method to study the biography of the Prophet (pbuh): An analytical and descriptive study of the book "The Sirat-E-Mustafa" (pbuh)" (in ar). Al-Azhār 8 (1): 28. doi:10.46896/alazhr.v8i01.304. ISSN 2519-6707. http://www.al-azhaar.org/index.php/alazhar/article/view/304. Retrieved 2023-06-30.
- ↑ Àdàkọ:Cite thesis
Ìtàkùn ìta
àtúnṣe- Seerat-e Mustafa at Internet Archive (Urdu)
- Seerat-e Mustafa at Internet Archive (English)
- Seerat-e Mustafa at Internet Archive (Bengali)