Segun Abraham

Olóṣèlú

şégun Abraham jẹ́ olóṣèlú àti gbajúmọ̀ oníṣòwò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress Ó gbégbá ìbò tí ó sìn díje lábẹ́ lé nínú ẹgbẹ́ òṣèlú APC fún ipò gómìnà ìjọba Ìpínlẹ̀ Oǹdó ní Ọdún 2016, [1][2] ṣùgbọ́n kò wọlé, Ọ̀gbẹ́ni Rótìmí Akérédolú ni ó wọlé lábẹ́ òṣèlú APC

ṣẹ́gun Abraham
Ọjọ́ìbíOlusegun Abraham
24 Oṣù Kejìlá 1953 (1953-12-24) (ọmọ ọdún 71)
Ikare-Akoko, Ondo State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèỌmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà
Iléẹ̀kọ́ gígaTyndale University College and Seminary Institute of Directors
Iṣẹ́Olóṣèlú àti oníṣòwò
Ìgbà iṣẹ́1999–present
Political partyAll Progressives Congress
Olólùfẹ́Bunmi Abraham
Websitesegunabraham.com

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe