Shehu Musa Yar'Adua
Shehu Musa Yar'Adua (March 5, 1943 – December 8, 1997) je omo orile-ede Naijiria to je onisowo, jagunjagun ati oloselu. Nigba ijoba ologun Ogagun Olusegun Obasanjo, Yar'Adua ni o je igbakeji olori orile-ede gege bi Oga Gbogbo Omose Ologun[1]. Yar'Adua ku ni ogba ewon ni ojo 8 osu 12, 1997 leyin atimole re lowo ijoba ologun Ogagun Sani Abacha nitori akitiyan re fun ijoba arailu.

Shehu Musa Yar'Adua |
---|
Shehu Musa Yar'Adua ni egbon Aare Naijiria tele Umaru Yar'Adua.
Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀
àtúnṣeYar'Adua wa lati ilu Katsina lati idile oba . Baba Musa Yar'Adua, je oluko,won je oye Minisita fun ọrọ Eko lati 1957 si 1966 nigba Naiijiria Orilẹ -ede Akọkọ won je oye Tafidan Katsina ni ilu Katsina ati Mutawallin Katsina (keeper of the treasury). Baba to bi baba Yar'Adua's , Malam Umaru je Mutawalli, aburo e Umaru Yar'Adua, je olori ede ti Naiijiria lati 2007 to 2010 .
Yar'Adua ka ile-ẹkọ ni Sẹkọndiri Katsina Middle School ati Katsina Provincial School (ti je Government College, Katsina) awon ati Muhammadu Buhari jo je ọmo ile -iwe naa.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |