Èdè Sindhi

(Àtúnjúwe láti Sindhi language)

Ede Sindhi (Sindhi: سنڌي, Urdu: سندھی,Devanagari script: सिन्धी, Sindhī) je ede ni agbegbe Sindh ni Pakistan loni. Iye awon eniyan to un so ni Pakistan je 24,410,910, bakanna ni India iye awon to n so je 2,535,485.[1] O je ede iketa ni Pakistan, ati ede ibise ni Sindh ni Pakistan. O tun je ede ibise ni India. Kadi idanimo ti ijoba ile Pakistan un te jade je ni ede meji nikan pere, Sindhi ati Urdu.

Sindhi
سنڌي , सिन्धी ,Sindhī
Sísọ níPakistan, India. Also Hong Kong, Oman, Philippines, Singapore, UAE, UK, USA, Afghanistan
AgbègbèSouth Asia
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀21 million[1]
Èdè ìbátan
Indo-European
Sístẹ́mù ìkọArabic, Devanagari, Laṇḍā
Lílò bíi oníbiṣẹ́
Èdè oníbiṣẹ́ níPakistan Sindh, Pakistan
Índíà India
Àkóso lọ́wọ́Sindhi Language Authority (Pakistan)
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-1sd
ISO 639-2snd
ISO 639-3snd
Indic script
Indic script
This page contains Indic text. Without rendering support you may see irregular vowel positioning and a lack of conjuncts. More...