Sobi FM (101.9 MHz) jẹ́ ilé-iṣẹ́ rédíò kan, tó wà ní ìlú Ilorin, ní Ìpínlẹ̀ Kwara, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Wọ́n ṣèdásílẹ̀ rẹ̀ ní ọjọ́ kẹwàá oṣù keje, ọdún 2017,[2] ó sì wà ní orí-òkè Sobi, ní òpópónà Shao.

Sobi FM Ilorin
CityIlorin
Broadcast areaKwara State
Frequency101.9 MHz
First air date10 Oṣù Keje 2017 (2017-07-10)
Language(s)English, Yoruba, Hausa, Nupe, Baruba, Fulfude
OwnerLukman Mustapha
Websitesobifm.com
Pákó Atọ́ka

Olùdásílẹ̀

àtúnṣe

Olùdásílẹ̀ Sobi FM ni Lukman Akanbi Olayiwola Mustapha, tó jẹ́ olóṣèlú ilẹ̀ Nàìjíríà, àti òṣìṣẹ́ báǹkì.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "SOBI 101.9 FM PLAYS HOST TO KWARA NOA". Retrieved 22 February 2020. 
  2. "SOBI FM 101.9 COMMISSIONING: SPEECH BY DIRECTOR GENERAL, (NBC)". Archived from the original on 22 February 2020. Retrieved 22 February 2020.