Soundcity Radio Network
Soundcity Rédíò Network jẹ́ ilé iṣẹ́ asọ̀rọ̀mágbèsì kan ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó ma ń ṣe àtòjọ àwọn orin ovójì tó lààmì laaka jùlọ ní ilẹ̀ Nàìjíríà lábẹ́ àṣe àti alákòóso Alphavision Multimedia tí ó jẹ́ ẹ̀ka Considated Media Associates (CMA). Olú ilé iṣẹ́ wọn wà ní Ìpínl Èkó . Ilé iṣẹ́ yí Ma ń gbóhùn sáfẹ́fẹ́ tí wọ́n sì ma ń ní ọ̀pọ̀ olùgbọ́ tí ó pọ̀ ju láàrín àwọn ọ̀dọ́ langba jákèjádò orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1][2]
Ifilole 98.5 ni ipinle Eko
àtúnṣeYíyẹ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ wọn wo Fún ìgbà ánọ́kọ́ ni ó bẹ̀rẹ̀ ní àárin ọdún 2016, ámọ́ ìṣètò ọlọ́kan ò jọ̀kan bbẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù Keje ọdún 2016 pẹ̀lú Ṣọlá Thompson. Ẹni tí ń ṣiṣẹ́ méjì pọ̀ gẹ́gẹ́ bí adarí ẹ̀ka ètò tí ó sì ń rukọ̀ 'Whats' Up Lagos Show láti ìdájí ní dédé agogo Mẹ́fà ìdájí sí agogo Mẹ́wá àárọ̀ (6-10am) igba akọkọ ati Ibusọ ita gbangba ilu Eko fun Nẹtiwọọki Redio ti o bẹrẹ ni akọkọ mẹẹdogun ọdun 2016 ṣugbọn siseto ati OAPs wa lori afefe ni ọjọ 18th ti Keje 2016 pẹlu Shola Thompson, ẹniti o ṣe ilọpo meji bi oludari eto ati Flo gbigbalejo 'Kini Kini Ifihan ti ilu Eko lati 6AM si 10AM (WAT). Àwọn OAP mìíràn tó tẹ̀le pẹ̀lú igbáẹ́fúnra ẹni láàrín wákàtí mẹ́rin. [2] [3]
Ìṣètò wọn
àtúnṣeOrin ni ó ja ilé iṣẹ́ Soundcity lógún jùlọ, tí wọ́n sì ma ń fi ìròyìnìròyìn ní ìrìnà, eré ìdárayá, gbèé lẹ́sẹ̀. [4]
Àwọn ibi tí ìtàkùn wọn de
àtúnṣe- Àtẹ ìsàlẹ̀ yí lò fi ibi í ìtàkùn wọn de hàn
Agbegbe | Freq. |
Eko | 98.5 MHz |
Abuja | 96,3 MHz |
Port Harcourt | 96,5 MHz |
Kano | 91,3 MHz |
Enugu | 91,1 MHz |
Uyo | Sibe lati Ifilole |
Èdè ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ wọn
àtúnṣe- Èdè Gẹ̀ẹ́sì
Àkókó ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́
àtúnṣe- 24/7 lori FM ati ṣiṣanwọle
Àwọn òṣìṣẹ́ wọn lọ́wọ́lọ́wọ́
àtúnṣe
|
ÀwọnÌtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Soundcity 98.5 Lagos, 98.5 FM, Lagos, Nigeria - Free Internet Radio". TuneIn. 2019-02-09. Retrieved 2019-12-04.
- ↑ 2.0 2.1 "Soundcity Radio Lagos Online". Radio.org.ng. 2017-06-01. Retrieved 2019-12-04.
- ↑ "Soundcity Radio 96.3 - FM 96.3 - Abuja". Streema. 2010-01-01. Retrieved 2019-12-04.
- ↑ Revolvy, LLC (2010-01-01). ""Soundcity Radio Network" on Revolvy.com". Revolvy. Retrieved 2019-12-04.
Ìtàkùn Ìjásóde
àtúnṣe- Official website