Stanley Ebuka Nzediegwu (tí wọ́n bí ní ọjọ́ karùndínlógún oṣù Karùn-ún ọdún 1989) tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí Stan Nze jé òṣèrékùnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó gbajúmọ̀ fún ìkópa rẹ̀ nínú fíìmù Rattlesnake.[1] Stan gba àmì-ẹ̀yẹ AMVCA fún fíìmù yìí ní ọdún 2022, gẹ́gẹ́ bí òṣèrékùnrin tó dára jù lọ.[2]

Stan Nze
Ọjọ́ìbíStanley Ebuka Nzediegwu
15 Oṣù Kàrún 1989 (1989-05-15) (ọmọ ọdún 35)
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaNnamdi Azikiwe University
Iṣẹ́Actor
Ìgbà iṣẹ́2009 - present
Gbajúmọ̀ fúnRattlesnake: The Ahanna Story
AwardsAMVCA Best Actor in a Drama

Ìgbésí ayé rẹ̀

àtúnṣe

Stan Nze gba oyè ẹ̀kọ́ nínú ìmọ̀ Computer Science ní Yunifásítì Nnamdi AzikiweAwka.[3] Ó tún kẹ́kọ̀ọ́ nípa eré-ṣíṣe ní Stella Damasus Arts Foundation.[1]

Ìṣàfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ wáyé ní ọdún 2009, nínú fíìmù Private Sector, lẹ́yìn náà ni ó kópa nínú fíìmù Murder At Prime Suites tó jáde ní ọdún 2013, tí ó ti ṣe ẹ̀dá-ìtàn apànìyàn alárùn ọpọlọ.[1]

Ó gbé arábìnrin Blessing Jessica Obasi níyàwó ní ọjọ́ kọkànlá oṣụ̀ kẹsàn-án ọdún 2021, ní ìlú Èkó.[1]

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀

àtúnṣe

Àwọn fíìmù àgbéléwò

àtúnṣe
Ọdún Àkọ́lé Ipa Àkọsílẹ̀ Ìtọ́ka
Ọdún 2013 Murder at Prime Suites Adolf First film role
Ọdún 2015 Bad Drop O tun ṣe iranṣẹ bi olupilẹṣẹ [4]
Ọdún 2016 Just not married Duke Nyamma [5]
2017 Omoye Peter [6]
2020 Rattlesnake: Itan Ahanna Ahanna [7]
2021 Prophetess Buntus [8]
Bitter Rain Ebuka [9]
Charge and Bail Dotun [10]
2021 Aki and Pawpaw [11]
2022 Hey You (fiimu 2022)

Àwọn ètò orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán

àtúnṣe
Ọdún Àkọ́lé Ipa Àkọsílẹ̀ Ìtọ́ka
2009 Private Sector [1]
Tinsel Ohakanu [12]
2016-17 This Is It Sam [13]

Àmì-ẹ̀yẹ àti yíyàn fún àmì-ẹ̀yẹ

àtúnṣe
Ọdún Àmì-ẹ̀yẹ Ìsọ̀rí Iṣẹ́ Èsì Ìtọ́ka
2016 Zulu African Film Academy Awards (ZAFAA) Best Lead Actor Just Not Married Wọ́n pèé [14]
2019 Best of Nollywood Awards Best Supporting Actor –English Thick Skinned Wọ́n pèé [15]
2020 Best of Nollywood Awards Best Actor in a Lead role –Igbo Ishi Anyaocha Wọ́n pèé [16]
2021 City People Movie Awards Best Actor Rattlesnake: The Ahanna Story Gbàá [17]
Best of Nollywood Awards Gbàá [18]
Best Kiss in a Movie Yàán [19]
2022 Africa Magic Viewers' Choice Awards Best Actor in A Drama Gbàá [19]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 1.4 "Two popular Nollywood stars don marry each oda" (in Nigerian Pidgin). https://www.bbc.com/pidgin/world-58535059.  Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name ":0" defined multiple times with different content
  2. "Stan Nze, Osas Ighodaro win big - Full list of all di winners from 2022 AMVCA". BBC News Pidgin (in Nigerian Pidgin). 2022-05-14. Retrieved 2022-07-26. 
  3. Oguntayo, Femi (2021-01-30). "9 showbiz stars to watch out for in 2021". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-11-14. 
  4. "Must watch movie of the year to be premiered this June". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-06-19. Retrieved 2021-09-17. 
  5. "Meet cast in new character posters". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-04-27. Retrieved 2021-09-17. 
  6. "Tina Mba, Stan Nze, others return in 'Omoye'". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-10-20. Retrieved 2021-09-17. 
  7. "Osas Ighodaro, Efa Iwara, Stan Nze to star in 'Rattle Snake' remake directed by Ramsey Nouah". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-09-02. Retrieved 2020-12-22. 
  8. "Niyi Akinmolayan's Mighty Prophetess". THISDAYLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-04-03. Retrieved 2021-09-17. 
  9. "Watch the official trailer for 'Bitter Rain'". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-08-05. Retrieved 2021-09-17. 
  10. "INKBLOT production releases trailer for high anticipated blockbuster, charge and bail". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-09-16. Retrieved 2021-09-16. 
  11. "'Aki and Pawpaw' remake rakes in N30 million in first week – P.M. News" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-29. 
  12. "17 actors you may have forgotten were on "Tinsel"". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-05-16. Retrieved 2021-09-17. 
  13. "Top 5 TV and web series of the year". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-12-12. Retrieved 2021-09-17. 
  14. "ZAFAA 2016: Ini Edo, Eniola Badmus, Stan Nze and more make nomination list". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-11-29. Retrieved 2021-09-17. 
  15. Bada, Gbenga (2019-12-15). "BON Awards 2019: 'Gold Statue', Gabriel Afolayan win big at 11th edition". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-10-10. 
  16. Augoye, Jayne (2020-12-02). "2020 BON: Here are 5 nominees for 'Best Kiss' category" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-10-11. 
  17. "OLAIDE ALMAROOF, ANIKE AMI, STAN NZE, others win in grand style at the 2021 City People Movies Award". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-08-31. Retrieved 2021-09-17. 
  18. "BBNaija Pere bags 'Best Actor' nomination in 2021 BON Awards". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-09-11. Retrieved 2021-09-17. 
  19. 19.0 19.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named AMVCA