Stella Jane Thomas (bíi ní ọdún 1906) jẹ́ agbejọ́rọ̀ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1][2] Òun ní obìnrin àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ adájọ́ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[3]

Stella Thomas
Ọjọ́ìbíStella Jane Thomas
1906
Lagos, Nigeria
Aláìsí1974 (aged 68)
Orílẹ̀-èdèNigerian
Orúkọ mírànStella Marke
Iṣẹ́Lawyer, magistrate
Ìgbà iṣẹ́1933–1974
Gbajúmọ̀ fúnFirst woman magistrate of Nigeria

Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Stella ní ọdún 1906 sí ìlú Èkó, ó sì jẹ ọmọ Peter John Claudius Thomas. Bàbá rẹ̀ ní ọmọ ilẹ̀ Áfríkà àkọ́kọ́ tí ó má jẹ́ adarí fún Lagos Chamber of Commerce.[4] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Annie Walsh Memorial School ní ìlú Freetown ní orílẹ̀ èdè Sierra Leone.[5] Ó gboyè nínú ìmò òfin láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Oxford University.[6]

Iṣẹ́

àtúnṣe

Thomas ni obìnrin àkọ́kọ́ láti ilẹ̀ Áfríkà tí ó má ṣe agbejọ́rọ̀ ni ìlú Britain ní ọdún 1933.[7] Òun sì ní obìnrin àkọ́kọ́ tí ó má jẹ́ agbejọ́rọ̀ ní West Áfríkà.[8] Ní ọdún 1943, ó di adájọ́ bìnrin àkọ́kọ́ ní West Africa[9] ní ilé ẹjọ́ tí ó wà ní Ikeja.[10] Ó kú ní ọdún 1974.[11]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Nigeria The Case for Peaceful and Friendly Dissolution. The Futility of the Land Use. p. 40. 
  2. Osun State College of Education (Ila Orangun, Nigeria). School of Languages (2007). School of Languages Conference Proceedings, Volume 1, Issue 1. Indiana University. p. 131. 
  3. Helen Tilley, Africa as a Living Laboratory: Empire, Development, and the Problem of Scientific Knowledge, 1870-1950 (University of Chicago Press, 2011): 429. ISBN 9780226803470.
  4. Emeka Keazor, "Notable Nigerians: Stella Thomas", NSIBIDI Institute (4 November 2014).
  5. Sillah, N. (8 February 2013). "The ugly face of a bad policy in Sierra Leone: or is it crass stupidity?". Sierra Leone Telegraph. http://www.thesierraleonetelegraph.com/?p=3316. 
  6. Marc Matera, Black London: The Imperial Metropolis and Decolonization in the Twentieth Century (University of California Press, 2015): 43–44. ISBN 9780520959903.
  7. "West African Lady Barrister Called to the Bar" Nigerian Daily Telegraph (11 May 1933): 1.
  8. Marc Matera, "Black Internationalism and African and Caribbean Intellectuals in London, 1919-1950"[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́] (PhD diss., Rutgers University, 2008): 35–36.
  9. Fongot Kini-Yen Kinni, Pan-Africanism: Political Philosophy and Socio-Economic Anthropology for African Liberation and Governance (Langaa RPCIG, 2015): 819. ISBN 9789956762767.
  10. Akaraogun, Olu (June 1966). "Memoirs of Stella Thomas, Our Pioneer Lady Barrister". Spear Magazine. 
  11. Emeka Keazor, "Notable Nigerians: Stella Thomas", NSIBIDI Institute (4 November 2014).