Ngozi Sylvia Oluchi Ezeokafor (tí a mọ̀ bi Sylvya Oluchy) jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Sylvya Oluchy
Sylvya Oluchy
Ọjọ́ìbíNgozi Sylvia Oluchi Ezeokafor
June 7
Lagos, Lagos State, Nigeria
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́2009–present
Websitehttp://sylvyaoluchy.com/

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

A bí Sylvia Oluchi ní Ìlú Èkó ó sì dàgbà ní Ìlú Àbújá[1] O kẹ́ẹ̀kọ́ Eré TíátàYunifásítì Nnamdi Azikiwe ti ìlú Awka, Ìpínlẹ̀ Anámbra

Iṣẹ́ ìṣe rẹ̀

àtúnṣe

Gẹ́gẹ́bí ó ti ṣe sọ, ìyá rẹ̀ ni ó ṣokùn fa bí ó ti ṣe di ẹni tí n ṣiṣẹ́ eré ìtàgé nígbà kan t́i ìyá rẹ̀ n ṣe àkàwé bí yóó ti ṣe ṣe dáada nídi iṣẹ́ òṣèré, lẹ́hìn ṣíṣe àkíyèsí rẹ̀ pẹ̀lú bí ó ti ṣe maá n sín àwọn olùkọ́ ilé-ìwé rẹ̀ jẹ.[2] Ní ọdún 2011, ó kó ipa ti Shaniqua nínu eré Atlanta. Nínu àwọn ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò kan pẹ̀lú Best of Nollywood Magazine àti YES International Magazine níbi tí wọ́n tí n bií léèrè láti mọ̀ bóyá ó ní àwọn ààlà nínu iṣẹ́ òṣèré rẹ̀, ó sọ di mímọ̀ wípé òun kò ní ààlà tàbí èèwọ̀ kankan tó bá di ṣíṣe iṣẹ́ òṣèŕe tí òún yàn láàyò. Ó tún jẹ́ kó di mímọ̀ wípé, kódà òun kò ní èyíkèyí ìṣòro pẹ̀lú ṣíṣeré oníhòhò.[3][4][5][6]

Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀

àtúnṣe
Ọdún Fíìmù Ipa Àwọn àkọsílẹ̀
2009 Honest Deceiver Lara as Sylvia Oluchi
2009 Honest Deceiver 2 Lara as Sylvia Oluchi
2010 Bent Arrows Idara[7]
2011 Atlanta Series Shaniqua
2013 Alan Poza Senami
2013 On Bended Knees
2013 Playing Victim Demeji's Girlfriend
Finding Love
2014 Being Mrs Elliot[8][9][10] Nonye
2015 Losing Control Coco
2015 Heroes and Villains
2018 Forbidden Chinalu

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Waiting In The Wings— Sylvia Oluchy". Nigeriafilms.com. 2010-09-05. Archived from the original on 2014-04-21. Retrieved 2014-04-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "My Ideal man must have high IQ". nationalmirroronline.com. Archived from the original on 15 August 2016. Retrieved 17 April 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "My Body is my Laptop and I don't have any problem acting Nude". leemagazineng.com. Archived from the original on 17 April 2014. Retrieved 17 April 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. "Fast Rising actress shares sexy photos". informationng.com. Archived from the original on 26 March 2014. Retrieved 17 April 2014. 
  5. "Sylvia Oluchi shares Raunchy Photos". insidenaija.com. Archived from the original on 19 April 2014. Retrieved 17 April 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. "Sylvia Oluchi interview with YES Magazine". yesinternationalmagazine.com. Archived from the original on 14 August 2018. Retrieved 19 April 2014. 
  7. "Sylvia Oluchi films on irokotv". irokotv.com. Archived from the original on 19 April 2014. Retrieved 17 April 2014. 
  8. "'Being Mrs Elliott' Watch movie review by Adenike Adebayo". Pulse Nigeria. Chidumga Izuzu. Archived from the original on 28 May 2015. Retrieved 28 May 2015. 
  9. "Nollywood movie review: Being Mrs. Elliot". Premium Times. Onyinye Muomah. Retrieved 28 September 2015. 
  10. "BEING MRS ELLIOT / OMONI OBOLI, MAJID MICHEL". 9FLIX. 9flix. Archived from the original on 13 June 2014. Retrieved 20 May 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)