Taofeek Oladejo Arapaja
Taofeek Oladejo Arapaja je oloselu omo ile Naijiria ati Igbakeji si Gomina Ipinle Oyo, Adebayo Alao-Akala lati 2007. Teletele, o je asoju ni Ile-igbimo Asofin Naijiria fun Ibadan South-West/Ibadan North-West Constituency lati 2003 de 2007 ati Alaga, Agbegbe Ijoba Ibile Guusu-Iwoorun Ibadan ni 1999 de 2003.
Taofeek Oladejo Arapaja | |
---|---|
Igakeji Gomina Ipinle Oyo | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga May 29, 2007 | |
Gómìnà | Adebayo Alao-Akala |
Asíwájú | Adebayo Alao-Akala |
Asoju Ile-Igbimo Asofin | |
In office May 29, 2003 – May 29, 2007 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Ibadan, Oyo State, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | PDP |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- Iforowanilenuwo ni 2005 [1] Archived 2005-11-17 at the Wayback Machine.