Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù-Ìwọòrùn Ìbàdàn
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
(Àtúnjúwe láti Agbegbe Ijoba Ibile Guusu-Iwoorun Ibadan)
Agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Gúúsù-Ìwọ̀òrùn Ìbàdàn jẹ́ ọ̀kan lára àwọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ tó wà ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, ní Nàìjíríà. Olú-ìlú rẹ̀ wà ní Oluyole Estate ní Ìbàdàn. Àwọn agbègbè tó wà ní ìlú náà ni Ring-Road, Oke-Ado, Oke-Bola Gege, Born-Photo, àti Isale-Osi.
Ibadan South-West | |
---|---|
Country | Nigeria |
State | Oyo State |
Government | |
• Local Government Chairman and the Head of the Local Government Council | Kehinde Adeyemi Akanni (PDP) |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
Ó ní ìwọ̀n ilẹ̀ tó tó 40 km2 àti iye ènìyàn tó tó 282,585 ni ìka orí tó wáyé ní ọdún 2006.
Kóòdù ìfìwéránṣẹ́ agbègbè náà ni 200.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Post Offices – with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 2009-10-07. Retrieved 2009-10-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)