Taye Taiwo
Taye Ismaila Taiwo jẹ́ àgbá Bọ́ọ̀lù ọmo orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó gbá bọ́ọ̀lù owó ẹ̀yìn fún orílè-èdè Nàìjíríà àti fún ẹgbẹ́ àgbágbọ́ọ̀lù RoPí. Wọ́n bi ní ọjọ́ kẹrin dínlógún oṣù kẹrin(April 16) ọdún 1985.
Taye Taiwo | |||
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Taye Ismaila Taiwo | ||
Ọjọ́ ìbí | 16 Oṣù Kẹrin 1985 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Lagos, Nigeria | ||
Ìga | 1.83 m (6 ft 0 in) | ||
Playing position | left back | ||
Club information | |||
Current club | Rovaniemen Palloseura | ||
Number | 46 | ||
Youth career | |||
2003–2004 | Gabros | ||
2004 | Lobi Stars | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2005–2011 | Marseille | 192 | (17) |
2011–2013 | Milan | 6 | (0) |
2012 | → QPR (loan) | 15 | (1) |
2012–2013 | → Dynamo Kyiv (loan) | 20 | (0) |
2013–2015 | Bursaspor | 27 | (2) |
2015–2016 | HJK Helsinki | 32 | (6) |
2017 | Lausanne | 13 | (0) |
2017 | AFC Eskilstuna | 9 | (0) |
2018– | RoPs | 11 | (0) |
National team | |||
2004–2012 | Nigeria | 54 | (8) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 23 August 2017. † Appearances (Goals). |
Iṣẹ́ rẹ̀ ní àwọn ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù
àtúnṣeLobi Stars
àtúnṣeLẹ́yìn tí ó ti lo ọdún kan nínú ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà Division 1 ní Gabros International. Wọ́n ra Taiwo wá si ìpele Nigeria Premier League, sínú ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Lobi Stars. Níbi tí ó tún ti lo ọdún kan .[1]
Olympique de Marseille
àtúnṣeNí ọdún 2005, nígbà tí ó pé ọmọ ogún ọdún, ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù ilẹ̀ Faranse kan ti o n je Olympique de Marseille gba Taiwo sinu iko won. Won ra Taiwo lati le ropo ogbeni Bixente Lizarazu ti o ti lo sinu egbe agbaboolu Bayern Munich. Taiwo lo gba boolu ti iko re Olympic Marseille fi jawe olubori fun iko agbaboolu Olympique Lyonnais ni 21 March 2010, pelu ese osi re lati ona to jin. Otun gba boolu sinu awon egbe agbaboolu US Boulogne ti o tun je ki iko Olympic Marseille o jawe olubori ni 17 April 2010. Ni ojo 23 April 2011, Taiwo naa lo tun se sababi ti egbe agbaboolu re fi jawe olubori ninu ifese-wonse to waye laari iko re pelu iko agbaboolu Montpellier HSC pelu ami ayo kan soso ni ori papa Stade de France ti o si je ki egbe agbaboolu re o gbe ife eye 2011 Coupe de la Ligue.[2] Leyin idije yii, Taiwo mu ero gbohun-gbohun lati fi idunnu re han pelu awon ololufe egbe agbabooolu re ni eyi ti o ku die ki won fun ni iwe gbele re fun odun kan lati owo ajo LFP.[3] Sibe, Taiwo si gba iwe gbele re fun ifese-wonse kan fun ohun ti o se naa ti o si padanu lati kopa ninu ifese-wonse ti o keyin Liigi naa, sugbon o bebe .[4] Bi o se wu Taiwo lati wa pelu egbe agbaboolu Marseille, o kede re lati fi egbe agba-boolu naa sile lopin odun naa[5] Ti oun yoo si po soke raja ni opin odun 2010-11.[6]
Milan
àtúnṣeNi May 9, 2011. Akoni moogba egbe agba-boolu A.C. Milan iyen Massimiliano Allegri, fi onte luu pe ki Taiwo o dara po mo iko re ti yoo si je amugba-legbe fun agba-boolu omo ile Faranse kan ti o n je Philippe Mexès. O ye ki awon mejeji o jo gba boolu papo fun iko won ni odun 2011–12.[7] Sugbon ninu idije akoko re ni o ti gba boolu kan si awon ti iko re AC Millan fi na iko agba-boolu Cesena ti o wa nile ni ami eyokan si oodo 1-0 ni 24 September 2011. Ni kete ti o gba gba boolu naa wole ni won fi Luca Antonini ropo re. Ni December 2011, Taiwo foro jomi toro oro pelu iwe iroyin ile Faranse kan L'Équipe ni bi ti o ti fi edun okan re han si bi inu re ko se dun si ohun ti oju re n ri ninu egbe agba-boolu re A.C. Milan, paa paa julo eyi ti o n ri lara akoni moogba re Massimiliano Allegri pelu bi ko se loo mo ninu awon ifese-wonse to tun waye.[8] Taiwo kabamo wipe oun i ba duro sinu egbe agba--boolu ile Italy ti oun wa tele ju bi oun n fidi rale lori aga ipaaro lasan lo .[9]
Queens Park Rangers
àtúnṣeNi 24 January 2012, Queens Park Rangers gba Taiwo wole sinu iko won lati inu egbe agba-boolu AC Milan pelu eyawo titi di opin odun naa, pelu alakale wipe awon yoo ra Taiwo ni Milionu meta ole maruun £3.5 M.[10] Leyin ti won ti se igbese lori QPR, Taiwo ni oun gbero lati mu ilapa ire wo egbe agba-boolu tun tun naa ju ki oun o ma joko lori aga ipaaro lasan lo.[11] O tun ja fita fita ni 1 February nigba ti iko re ba iko Aston Villa pade ni Birmingham, ninu ifese-wonse ti o pari si eji eji 2–2. Taiwo pinu wipe oun yoo duro si inu egbe agba-boolu Queens Park Rangers.[12] O gba boolu akoko re sinu awon pelu Free kick ti o to iwon ese bata metadin-logbon 27 yards ti won si lu iko Sunderland pelu ami ayo meta si okan 3-1 ni 24 March 2012.[13]
Dynamo Kyiv
àtúnṣeNi 31 July 2012, Taiwo dara po mo egbe agba-boolu ile Ukrainian kan Dynamo Kyiv pelu yiya ofe, pelu alakale wipe won yoo ra lopin odun naa.[14]
Bursaspor
àtúnṣeNi 5 July 2013, Taiwo tun kowo bowe lati gba boolu fun egbe agba-boolu ile Turkey kan Bursaspor fun odun meta[15] Egba agba-boolu Cardiff City fe kowo le lati le mu lo si idije Premier Legue, sugbon o pinu lati ba egbe agba-boolu ile Turkey naa lo.[16] Ni 1 August 2013, Taiwo gba boolu ti o je ki iko re gba omi 2-2 draw pelu iko Vojvodina ninu iffese-wonse akoko Europa League.[17] Ni 27 April 2015, Taiwo gba lati fopin si ibasepo re pelu iko re Bursaspor.[18]
HJK
àtúnṣeNi 23 August 2015, Taiwo dara po mo egbe gba-boolu HJK ti odun na fi pari ti o si tun lo odun kan si pelu won.[19] Ni osu October odun kan naa, HJK gba Taiwo wole fun idije ti odun 2016.[20][21] .[22]
Lausanne-Sport
àtúnṣeNi 30 January 2017, Taiwo dara po mo Lausanne titi di opin odun 2016/17.[23]
AFC Eskilstuna
àtúnṣeTaye Taiwo tun dara po mo Allsvenskan , AFC Eskilstuna fun ipari idije August odun 2017.
Alaye lori awon egbe agba-boolu re to ti dara po mo
àtúnṣeEgbe agba-boolu
àtúnṣeClub | Season | League | National Cup | League Cup | Continental | Other1 | Total | |||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Division | Apps | Goals | Apps | Goals | Apps | Goals | Apps | Goals | Apps | Goals | Apps | Goals | ||
Marseille | 2004–05 | Ligue 1 | 4 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | — | 4 | 0 | |
2005–06 | 30 | 1 | 1 | 0 | 1 | 0 | 9 | 1 | — | 41 | 2 | |||
2006–07 | 38 | 3 | 1 | 0 | 0 | 0 | 2 | 1 | — | 41 | 4 | |||
2007–08 | 28 | 3 | 1 | 0 | 1 | 0 | 10 | 2 | — | 40 | 5 | |||
2008–09 | 35 | 3 | 2 | 1 | 1 | 0 | 14 | 0 | — | 52 | 4 | |||
2009–10 | 27 | 3 | 1 | 0 | 1 | 0 | 8 | 0 | — | 37 | 3 | |||
2010–11 | 30 | 4 | 1 | 0 | 4 | 1 | 5 | 0 | 1 | 0 | 41 | 5 | ||
Total | 192 | 17 | 7 | 1 | 8 | 1 | 48 | 4 | 1 | 0 | 256 | 23 | ||
Milan | 2011–12 | Serie A | 4 | 0 | 0 | 0 | — | 4 | 0 | — | 8 | 0 | ||
2012–13 | 0 | 0 | 0 | 0 | — | — | — | 0 | 0 | |||||
Total | 4 | 0 | 0 | 0 | — | 4 | 0 | — | 8 | 0 | ||||
Queens Park Rangers (loan) | 2011–12 | Premier League | 15 | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | — | — | 15 | 1 | ||
Dynamo Kyiv (loan) | 2012–13 | Vyshcha Liha | 20 | 0 | 1 | 1 | — | 10 | 0 | — | 31 | 1 | ||
Bursaspor | 2013–14 | Süper Lig | 27 | 2 | 8 | 0 | — | 2 | 1 | — | 37 | 3 | ||
2014–15 | 0 | 0 | 0 | 0 | — | — | — | 0 | 0 | |||||
Total | 27 | 2 | 8 | 0 | — | 2 | 1 | — | 37 | 3 | ||||
HJK | 2015 | Veikkausliiga | 11 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | — | 11 | 0 | |
2016 | 21 | 6 | 3 | 0 | 5 | 2 | 0 | 0 | — | 29 | 8 | |||
Total | 32 | 6 | 3 | 0 | 5 | 2 | 0 | 0 | — | 40 | 8 | |||
Lausanne-Sport | 2016–17 | Swiss Super League | 1 | 0 | 0 | 0 | — | — | — | 1 | 0 | |||
Career total | 291 | 26 | 19 | 2 | 11 | 3 | 66 | 5 | 1 | 0 | 388 | 36 |
- 1 Includes Trophée des champions
International
àtúnṣeNigeria | ||
---|---|---|
Year | Apps | Goals |
2004 | 1 | 0 |
2005 | 2 | 0 |
2006 | 8 | 1 |
2007 | 9 | 3 |
2008 | 12 | 0 |
2009 | 4 | 0 |
2010 | 7 | 0 |
2011 | 9 | 1 |
2012 | 1 | 0 |
Total | 53 | 5 |
Statistics accurate as of match played 29 February 2012[24]
International goals
àtúnṣeNo | Date | Venue | Opponent | Score | Result | Competition | Ref |
---|---|---|---|---|---|---|---|
1. | 23 January 2006 | Port Said Stadium, Port Said, Egypt | Ghana | 1–0 | 1–0 | 2006 Africa Cup of Nations | |
2. | 6 February 2007 | Griffin Park, London, England | Ghana | 1–3 | 1–4 | Friendly | [25] |
3. | 17 June 2007 | Stade Général Seyni Kountché, Niamey, Niger | Niger | 2–1 | 3–1 | 2008 Africa Cup of Nations qualification | [26] |
4. | 20 November 2007 | Letzigrund, Zürich, Switzerland | Switzerland | 1–0 | 1–0 | Friendly | [27] |
5. | 9 February 2011 | Teslim Balogun Stadium, Lagos, Nigeria | Sierra Leone | 1–0 | 2–1 | Friendly | [28] |
Awon ife to ti gba
àtúnṣeEgbe agba-boolu
àtúnṣe- Marseille
- Ligue 1: 2009–10
- Coupe de la Ligue: 2010, 2011
- Trophée des Champions: 2010
- UEFA Intertoto Cup: 2005
- Milan
- Supercoppa Italiana: 2011
Individual
àtúnṣe- 2005 FIFA World Youth Championship silver medal
- 2005 FIFA World Youth Championship bronze ball
- Confederation of African Football Young Player of the Year: 2006
- Ligue 1 Team of the Year: 2008, 2009, 2011
- Africa Cup of Nations: Team of all Tournaments
Awon itoka si
àtúnṣe- ↑ Italy take note of Taye Taiwo Archived 2013-01-04 at archive.ph Error: unknown archive URL. MTN. 16 September 2011. Retrieved 6 December 2011.
- ↑ Taye Taiwo elu joueur ICM du match Archived 26 May 2012 at the Wayback Machine.. (in French). new.lfp.fr. Retrieved 6 December 2011.
- ↑ Taiwo facing ban for taking mic out of PSG Archived 2011-04-29 at the Wayback Machine.. soccernet.espn.go.com (ESPN). Retrieved 6 December 2011.
- ↑ "Taiwo banned for chant". Sky Sports. 16 May 2011. http://www1.skysports.com/football/news/11095/6935577/. Retrieved 13 July 2013.
- ↑ "Taiwo keen for new deal". Sky Sports. 15 October 2010. http://www1.skysports.com/football/news/11095/6446445/. Retrieved 13 July 2013.
- ↑ "Taiwo knows next destination". Sky Sports. 7 April 2011. http://www1.skysports.com/football/news/11095/6857419/. Retrieved 13 July 2013.
- ↑ AC Milan confirm deals for Philippe Mexes and Taye Taiwo Archived 2011-05-12 at the Wayback Machine.. soccernet.espn.go.com (ESPN). Retrieved 6 December 2011.
- ↑ "Football - Taiwo "breaks", Milan is on Maxwell" (in Italian). Yahoo! Eurosport. 12 December 2011. http://it.eurosport.yahoo.com/12122011/45/calciomercato-taiwo-rompe-milan-maxwell.html.
- ↑ Taye Taiwo wants AC Milan stay. eyefootball.com. Retrieved 6 December 2011.
- ↑ "QPR seal loan deal for Taiwo". ESPN Soccernet. 24 January 2012. Archived from the original on 27 January 2012. https://web.archive.org/web/20120127161322/http://soccernet.espn.go.com/news/story/_/id/1012589/qpr-seal-loan-deal-for-nigeria-left-back-taye-taiwo?cc=5901.
- ↑ "Taye Taiwo targets immediate impact at QPR as loan move from AC Milan nears completion". Goal.com. 20 January 2012. http://www.goal.com/en-gb/news/2896/premier-league/2012/01/20/2857450/taye-taiwo-targets-immediate-impact-at-qpr-as-loan-move-from. Retrieved 13 July 2013.
- ↑ Taiwo: "I tifosi del Milan non credono in me, resto al QPR"
- ↑ "Sunderland A.F.C. 3 - 1 Queens Park Rangers". BBC Sport. 24 March 2012. https://www.bbc.co.uk/sport/0/football/17412343.
- ↑ "A.C. Milan comunicato ufficiale" (in Italian). acmilan.com (Associazione Calcio Milan). 31 July 2012. http://www.acmilan.com/it/news/breaking_news_show/29155. Retrieved 31 July 2012.
- ↑ "Nigeria's Taye Taiwo seals Bursaspor switch from Milan". BBC Sport. 7 July 2013. https://www.bbc.co.uk/sport/0/football/23217649. Retrieved 13 July 2010.
- ↑ "Taiwo snubbed Cardiff to join Bursaspor". Goal.com. 8 July 2013. http://www.goal.com/en-gb/news/2892/transfer-zone/2013/07/08/4103264/taiwo-snubbed-cardiff-to-join-bursaspor?ICID=CP_703. Retrieved 13 July 2013.
- ↑ "Vojvodina 2 - 6 Bursaspor". UEFA.com. 1 August 2013. http://www.uefa.com/uefaeuropaleague/season=2014/matches/round=2000467/match=2012381/index.html. Retrieved 2 August 2013.
- ↑ "Kamuoyunun Dikkatine !" (in Turkish). Bursaspor. 27 April 2015. http://www.bursaspor.org.tr/bs//haber?id=19910/27/04/2015/kamuoyunun_dikkatine_.
- ↑ "HJK SOPIMUKSEEN TAYE TAIWON KANSSA". http://www.hjk.fi/ (in Finnish). HJK. 23 August 2015. Retrieved 23 August 2015. External link in
|website=
(help) External link in|website=
(help) - ↑ "Taye Taiwo extends HJK Helsinki contract". The Nation Nigeria. 21 October 2015. Retrieved 27 October 2015.
- ↑ "TAIWO, DÄHNE JA ATOM JATKAVAT KLUBISSA". http://www.hjk.fi/ (in Finnish). Helsingin Jalkapalloklubi. 20 October 2015. Retrieved 20 October 2015. External link in
|website=
(help) External link in|website=
(help) - ↑ "Taye Taiwo quits Finnish club HJK Helsinki" (in English). Goal.com. 24 October 2016. Retrieved 24 October 2016.
- ↑ "TAYE TAIWO S’ENGAGE AVEC LE FC LAUSANNE-SPORT". lausanne-sport.ch (in French). Lausanne Sport. 30 January 2017. Retrieved 7 February 2017.
- ↑ Àdàkọ:NFT player
- ↑ "Glorious Ghana trounce Super Eagles". www.theguardian.com. The Guardian. 7 February 2007. Retrieved 10 February 2016.
- ↑ "Nigeria clinch Group Three". news.bbc.co.uk. BBC Sport. 19 June 2007. Retrieved 10 February 2016.
- ↑ "Nigeria defeat sees Swiss end year with negative balance". espn.go.com. ESPN. 20 November 2007. Retrieved 10 February 2016.
- ↑ "Siasia starts with a win for Super Eagles". www.kickoff.com. Kick Off. 9 February 2011. Archived from the original on 3 March 2016. Retrieved 10 February 2016.
Awon ijapo ita
àtúnṣe- Taye Taiwo - FIFA competition record