Temmie Ovwasa

Akọrin obìnrin

Temmie Ovwasa tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkàndínlógúnọ́gbọ̀n oṣù kọkànlá ọdún 1996 ni gbogbo ènìyàn mọ́ sí YBNL princess,[1] ni ó jẹ́ olórin , olùkọrin, àti òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, tí ó sì ń akọrin pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ agbórin-jáde YBNL Nation nígbà tí ó fọwọ́ sí ìwé àdéhùn pẹ̀lú wọn ní inú oṣù kẹjọ ọdún 2015[2] amọ́ tí ó kúrò ní ilé-iṣẹ́ náà ní inú ọdún 2020 lẹ́yìn tí èdè oun ati Olamide tí ó ni ilé-iṣẹ́ náà kò fẹ́ jọra mọ́.[3][4] Ovwasa ni ó fi hàn fáyé wípé obìnrin bí ẹgbẹ́ oun ni òun nífẹ́ sí láti ma bá ṣe àṣepọ̀.[5][6] Nígbà tí ó di ọdún 2020, ó gbé orin rẹ̀ akọ́kọ́ irú rẹ̀ tí ó ke nípa bí ọkùnrin ṣe ń ní àṣepọ̀ pẹ́lú ọkùnrin ẹgbẹ́ rẹ̀, èyí tí yóò mú kí ó jẹ́ irúfẹ́ rẹ̀ akọ́kọ́ irú rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[7]

Temmie Ovwasa
Ọjọ́ìbíTemmie Ovwasa
29 Oṣù Kọkànlá 1996 (1996-11-29) (ọmọ ọdún 28)
Ilorin, Ìpínlẹ̀ Kwara
Iṣẹ́
  • Singer
  • songwriter
  • Artist
Ìgbà iṣẹ́2016 - present
Musical career
Irú orin
InstrumentsVocals, Guiltar
Associated actsFireboydml

Ibẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Ovwasa ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n ìṣe kọkànlá ọdún 1996 ní ìlú Ìlọrin tí bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Delta tí Ìyá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun.[8][9] Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Grace Christian Schools tí ó sì lọ sílé ẹ̀kọ́ girama ti Dalex Royal College, ní Ìlọrin. Ó kẹ́kọ́ nípa Medical Anatomy nílé ẹ̀kọ́ Ladoke Akintola University of Technology.[10][11]

Iṣẹ́ orin rẹ̀

àtúnṣe

Temmie bẹ̀rẹ̀ orin rẹ̀ làti nkan bí ọmọ ọdún mẹ́jọ gẹ́gẹ́ bí akọrin ní ilé-ìjọsìn wọn níbi tí ó ti kọ́kọ́ gbé orin tirẹ̀ sílẹ̀.

[12] Látàrí ẹ̀bùn orin tí ó ní yí, ìyá rẹ̀ ra jìtá tuntun kan fun nígbà tí ó lé ọmọ ọdún méjìlá.[13] Ó di gbajú-gbàjà ní ọdún 2015 nígbà tí Olamide pèé lórí Instagram tí ó sì gbà á wọlé sí inú ilé-iṣẹ́ agbórin-jáde rẹ̀ YBNL níbi tí Temmie ti gba ìnagijẹ ''YBNL princess''. s[14] Temmie sì fi YBNL sílẹ̀ lẹ́yìn aìgbọ́ra ẹni yé tí ó ṣẹlẹ̀ láàrin òun ati Olamide.[15][16]

Àwọn àwo orin rẹ̀

àtúnṣe
  • E be like say dem swear for me (2020)[17]

Orin àdákọ rẹ̀

àtúnṣe
  • Afefe (2016)
  • Jabole (2016)
  • Bamidele (2017)
  • Holy Water (2018)
  • Osunwemimo (2020)
  • Elejo wewe (2020)

Àwọn ìtọ́ka sí

àtúnṣe
  1. "YBNL Princess Accuses Olamide Of Limiting Her Growth In The Music Industry". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-12-07. Archived from the original on 2021-02-17. Retrieved 2021-06-28. 
  2. "How Olamide destroyed my career for 5 years – Temmie Ovwasa". P.M. News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-12-07. Retrieved 2021-06-28. 
  3. "YBNL Princess Accuses Olamide Of Limiting Her Growth In The Music Industry". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-12-07. Archived from the original on 2021-02-17. Retrieved 2021-06-28. 
  4. Oladimeji (2020-12-04). "YBNL Princess Reveals Why She Refused To Change Name Despite Leaving Olamide’s Label | 36NG" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-28. 
  5. "I Found Out That I'm A Lesbian At 5 –Temmie Onwasa - New National Star" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-28. 
  6. Olowolagba, Fikayo (2021-03-13). "I’m disgusted by heterosexuality - Temmie Ovwasa". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-28. 
  7. "Temmie Ovwasa dropped Nigeria's first-ever openly gay album, and it is amazing!". The Rustin Times (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-12-28. Retrieved 2021-06-07. 
  8. "I’ve written over 300 songs – Temmie Ovwasa, aka YBNL Princess". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-07-09. Retrieved 2021-06-28. 
  9. "Temmie Ovwasa YBNL Princess Biography | Profile | FabWoman". FabWoman | News, Style, Living Content For The Nigerian Woman (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-12-08. Retrieved 2021-06-07. 
  10. Kalau, Nina (2017-06-22). "YNBL princess biography: You will LOVE this Super Star!". Legit.ng - Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-28. 
  11. "Temmie Ovwasa Biography: Things You Didn’t Know About". Hintnaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-03-02. Archived from the original on 2021-06-07. Retrieved 2021-06-07. 
  12. "Temmie Ovwasa Biography: Things You Didn’t Know About". Hintnaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-03-02. Archived from the original on 2021-06-07. Retrieved 2021-06-07. 
  13. Lala, Emmanuel (2016-07-11). "YBNL Princess, Temmie Ovwasa Talks How She Got A Record Deal From Olamide, Her Ideal Man & More | 36NG" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-28. 
  14. "Interview: Temmie Ovwasa Embraces the Complexity of Queerness In Nigeria". OkayAfrica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-02-09. Retrieved 2021-06-07. 
  15. "How Olamide destroyed my career for 5 years – Temmie Ovwasa". P.M. News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-12-07. Retrieved 2021-06-28. 
  16. Olowolagba, Fikayo (2020-12-08). "Temmie Ovwasa reconciles with Olamide". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-28. 
  17. E be like say dem swear for me (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), retrieved 2021-06-28 

Àdàkọ:Authority control