Tourcoing
- Tourcoing wa ni ipoidojuko 50°43′18″N 3°09′33″E / 50.7217°N 3.1593°ECoordinates: 50°43′18″N 3°09′33″E / 50.7217°N 3.1593°E
Tourcoing (ìpè Faransé: [tuʁ.kwɛ̃]) jẹ́ ìlú kan ní apá àríwá Fránsì, nítòsí ìlú Mouscron nílẹ̀ Bẹ́ljíọ̀m àti ìlú Roubaix. Agbègbè náà tóbi tó 15.19 km², tí àwọn ènìyàn inú rẹ̀ sí jẹ́ 93,974 nígbà ìkànìyàn ọdún 2013.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- Ojú-òpó wẹ́ẹ̀bù (Faransé)
- Ìrìn-àjò Afẹ́ (Faransé) (Gẹ̀ẹ́sì)