Umo Eno
Umo Bassey Eno tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹrìnlélógún oṣù kẹrin ọdún 1964, jẹ́ olùṣọ́ àgùtàn ilé-ìjọsìn All Christain Ministary International àti olóṣèlú tí ó tún jẹ́ gómìnà ní Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom nínú ìdìbò tó wáyé ní ọdún 2023., ó sì jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [1][2] Òun ni kọmíṣánà tẹ́lẹ̀ rí fún ọ̀rọ̀ ilẹ̀ àti omi àlùmọnì fún ìpínlẹ̀ Akwa Ibom. [3][4]
Umo Eno | |
---|---|
Governor of Akwa Ibom | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 29 May 2023 | |
Deputy | Akon Eyakenyi |
Asíwájú | Udom Emmanuel |
Akwa Ibom State Commissioner for Lands and Water Resources | |
In office 2021–2022 | |
Gómìnà | Udom Emmanuel |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 24 Oṣù Kẹrin 1964 Nsit-Ubium, Eastern Region, Nigeria (now in Akwa Ibom State) |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Peoples Democratic Party |
Alma mater | University of Uyo |
Occupation |
|
Ibẹ̀rẹ̀ ayé ati ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣewọ́n bí ní ọjọ́ Kẹrìnlélógún oṣù kẹrin ọdún 1964, ní ìlú rẹ̀ Ikot Ekpene Ìró tí ó wà ní abẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ Nsit-Ubium.[5] Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Local Authority Primary School tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó, níbi tí ó ti gba ìwé ẹ̀rí ẹ̀kọ́ akọ́bẹ̀rẹ̀ [6] He attended Local Authority primary school in Lagos State, where he got his first school leaving certificate.[7] Ó tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ sẹ́kọ́ndìrì ti St. Francis tí ó wa ní ilú Eket tí ó sì parí ìpele ẹ̀kọ́ yí ní Victoey High School tí ó wà ní Ìkẹjà ní ípínlẹ̀ Èkó .[7] Ó gba ìwé-ẹ̀rí ẹ̀kọ́ agba jáde nínú ìmọ̀ Ìbáṣepọ̀ Àwùjọ ní ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì Uyo tí ó sì gba ìwé ẹ̀rí Masters jáde nínú ẹ̀ka ìmọ̀ yí kan náà.[8]
Iṣẹ́nṣe rẹ̀
àtúnṣeWọ́n gbàá sisẹ́ ní ilé-iṣẹ́ Union Bank lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ sẹ́kọ̀ndìrì rẹ̀ ṣáájú kí ó tó lọ ṣiṣẹ́ ní ilé-iṣẹ́ Bertola Machine Tools Nigeria Limited àti Norman Holdings Limited, níbi tí ó ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọ̀gá àgbà ṣáájú kí ó tó lọ dá ilé-iṣẹ́ Royalty Group tí ó jẹ́ olùdásílẹ̀ rẹ̀.[8] Wọ́n yànán sí ipò kọmíṣánà fún ọ̀rọ̀ ilẹ̀ ati omi àlùmọ́nì ní Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom ní ọdún 2021 lábẹ́ gómìnà Udom Emmanuel[9][10][11] Ó kọ̀wé dupò náà sílẹ̀ láti díje du ipò Gómìnà ní Ìpínlẹ̀ náà ní ọdún 2023. [12][13]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Online, Tribune (2023-03-19). "PDP’s Umo Eno wins Akwa Ibom guber election with wide margin". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-03-20.
- ↑ Vanguard (2023-03-19). "Breaking: INEC declares PDP’s Umo Eno winner of Akwa Ibom guber poll". Vanguard. Retrieved 2023-03-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "11 things we know about Gov Emmanuel’s preferred successor, Eno". www.premiumtimesng.com. Retrieved 2023-03-20.
- ↑ "Pastor Umo Eno Marks 50th Birthday". 2014-05-10. https://www.channelstv.com/2014/05/10/pastor-umo-eno-marks-50th-birthday/amp/.
- ↑ Rapheal (2023-03-17). "Decision Day 2023: Those who will be governors". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-03-20.
- ↑ Rapheal (2023-03-17). "Decision Day 2023: Those who will be governors". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-03-20.
- ↑ 7.0 7.1 "Umo Eno… Barracks Boy who wants to be governor". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-03-11. Archived from the original on 2023-03-20. Retrieved 2023-03-20.
- ↑ 8.0 8.1 Rapheal (2022-05-23). "Bassey Umo Eno: Barracks boy you did not know". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-03-20.
- ↑ "Udom Emmanuel swears in four commissioners, five perm secs". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-01-03. Retrieved 2023-03-20.
- ↑ "Udom swears in new commissioners, perm secretaries - Businessday NG". businessday.ng. Retrieved 2023-03-20.
- ↑ Anthony, Lovina (2021-01-11). "APC stalwart congratulates Gov.Emmanuel's new appointees, warns against politics of prejudice". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-03-20.
- ↑ Online, Tribune (2022-03-24). "Akwa Ibom Assembly clears 6 Commissioner-nominees for swearing-in". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-03-20.
- ↑ THEWILL, Udeme Utip. "Gov Udom Sacks Six Commissioners Including His Preferred Successor – THEWILL NEWS MEDIA" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-03-20.