Up North jẹ́ fíìmù àgbéléwò tí ó jáde láti ọwọ́ Anakle Films and Inkblot Productions [2]ní ọdún 2018 ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí diTope Oshin[3] ṣe olùdarí rẹ̀. Naz Onuzo and Bunmi Ajakaiye ló kọ ire náà látàrí itan tí Editi Effiong kọ.[4] Ní ìlú Bauchi ni wọ́n ya iṣẹ́ náà, pẹ̀lú yíya ọ̀sẹ̀ kan ní ìlú Èkó Lagos.[5]

Up North
Fáìlì:Up North Poster.jpg
Theatrical release poster
AdaríTope Oshin
Olùgbékalẹ̀
  • Isioma Osaje
  • Zulumoke Oyibo
Àwọn òṣèréÀdàkọ:Startplainlist
Orin
  • Ré Olunuga
  • Gray Jones Ossai
Ìyàwòrán sinimáPindem Lot
Kagho Bichop Idhebor
OlóòtúBanjo Onyekachi Ayodele
Ilé-iṣẹ́ fíìmùAnakle Films
Inkblot Productions
OlùpínFilmOne Entertainment
Déètì àgbéjáde28 December 2018
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Èdè
  • English
  • Hausa
  • Pidgin
Owó àrígbàwọlé₦94 million[1]

Àwọn akópa

àtúnṣe

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe