Usman Dakingari

Olóṣèlú

Saidu Usman Nasamu Dakingari je oloselu omo ile Naijiria ati Gomina Ipinle Kebbi lati odun 2007.

Usman Sa'idu Nasamu Dakingari
Governor of Kebbi State
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
29 May 2007
AsíwájúAdamu Aliero
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí13 Oṣù Kẹ̀sán 1959 (1959-09-13) (ọmọ ọdún 64)
Dakin Gari, Kebbi State, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party (PDP)

Ni 30 June, 2007 Dakingari gbe Zainab Yar'Adua to je omo Aare Umaru Yar'Adua ni iyawo.[1]


Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "Yar’Adua’s daughter weds Kebbi governor". Archived from the original on 2022-05-26. Retrieved 2009-12-04.