Victor Osimhen

Agbabọọlu ẹgbẹ Naijiria

Victor James Osimhen tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1989 (29th December 1998) jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà agbábọ́ọ̀lù ṣiṣẹ́ ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Lille tí orílẹ̀ èdè France. Òun ni agbaboolu sáwọ̀n tó dára jù lọ fún ikọ̀ rẹ̀ lọ́wọ́́lọ́wọ́.[1] [2] [3] [4] Ní ọdún 2020, wọ́n tari Osimhen lọ sí inú ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Napoli nínú ìdíje Serie A club pẹ̀lú iye owó tí ó tó €70 million.

Victor Osimhen
Personal information
OrúkọVictor James Osimhen Victor Osimhen (LOSC) (cropped)
Ọjọ́ ìbí29 Oṣù Kejìlá 1998 (1998-12-29) (ọmọ ọdún 25)
Ìga1.86 m
Playing positionForward
Club information
Current clubLille
Number7
Youth career
0000–2017Ultimate Strikers Academy
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2017–2019VfL Wolfsburg12(0)
2018–2019Charleroi (loan)34(19)
2019Charleroi0(0)
2019–Lille18(10)
National team
2015Nigeria U177(10)
2015Nigeria U204(3)
2017–Nigeria9(4)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 6 December 2019.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 17 November 2019

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Osimhrn ní Ìpínlẹ̀ Èkó nígbà tí awọn òbí rẹ̀ jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Edo. Osimhen fẹ́ràn kí ó ma gbá bọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá látàrí wípé ó fẹ́ di ẹlẹ́sẹ̀ ayò bí gbajú-gbajà agbá bọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-èdè Côte d'Ivoire ìyẹn Didier Drogba.[5]


Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Àdàkọ:Worldfootball.net
  2. "Wolfsburg in deal for young Nigerian Victor Osimhen". BBC Sport. 2017-01-01. Retrieved 2020-01-05. 
  3. "Victor Osimhen - Player profile 19/20". Transfermarkt (in Èdè Jámánì). Retrieved 2020-01-05. 
  4. "Victor Osimhen Archives - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Retrieved 2020-01-05. 
  5. "Didier Drogba is my idol - Nigeria U17 striker Victor Osimhen". ESPN. 28 October 2015. Retrieved 21 February 2021.