Victor Osuagwu jẹ́ òṣèrékùnrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó ti gba àmì-ẹ̀yẹ ní City People Entertainment Awards,[1] ó sì fìgbà kan jẹ́ ààrẹ̀ ti Actors Guild of Nigeria, ẹka ti ìpínlẹ̀ Èkó.[2][3][4]

Victor Osuagwu
Ọjọ́ìbíVictor Ifeanyichukwu Osuagwu
March 6
Imo State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Port Harcourt
Iṣẹ́Actor
Olólùfẹ́Roseline Nchelem
AwardsCity People Movie Special Recognition Award

Ìgbésí ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ àtúnṣe

Agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Mbaise ní Ipinle Imo ni Osuagwu ti wá. Ìlú Surulere, ní Ìpínlẹ̀ Èkóló dàgbà sí Ó parí ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, níbi tí ó ti gba ìwé-ẹ̀rí WAEC.[5]

Iṣẹ́ tó yàn láàyò àtúnṣe

Osuagwu di mímọ̀ gẹ́gẹ́ bí i òṣèrékùnrin ní ọdún 1997. Fíìmù àkọ́kọ́ tó kópanínú rẹ̀ ni apá kejì fíìmù àgbéléwò kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Evil Passion 2, lásìkò tó ṣì jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ní ilé-ìwé gíga.[6]

Àṣààyàn àwọn fíìmù rẹ̀ àtúnṣe

  • Keke Soldiers
  • Professional Beggars
  • My Classmate
  • Corporate Beggar
  • Evil Passion
  • Evil Passion 2
  • One Dollar (pẹ̀lú Patience Ozokwor)
  • Adam Goes to School
  • He Goat
  • Ofeke
  • My Only Love
  • Lion Finger
  • Our Daily Bread
  • Onye Amuma (pẹ̀lú Nkem Owoh)
  • The Chronicles (pẹ̀lú Onyeka Onwenu àti Segun Arinze)[7][8]
  • Bird Flu
  • Powerful Civilian
  • Anti-Crime
  • Chelsea/Liverpool
  • Men On The Run
  • My Kingdom Come
  • Store Keeper
  • Tears From Holland
  • Joshua
  • Trouble Makers
  • My Only Love
  • No Shaking (pẹ̀lú Chiwetalu Agu àti Sam Loco Efe)
  • Nwa Teacher
  • Slow Poison
  • Onye-Eze
  • Agaba

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. Emmanuel, Daniji (2017-10-18). "Full List Of Winners At The 2017 City People Movie Awards". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-01. 
  2. "Victor Osuagwu emerges Lagos AGN president". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2013-06-17. Retrieved 2019-12-01. 
  3. "AGN Lagos: Victor Osuagwu hands over to Don Pedro-Aganbi". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-12-17. Retrieved 2019-12-01. 
  4. "Honour Comes for Victor Osuagwu, as Actor Reaches Out to Children". guardian.ng. 23 January 2015. Retrieved 2019-12-01. 
  5. "Why we created Nollywood Comedy Club –Victor Osuagwu". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 21 April 2017. Retrieved 2019-12-01. 
  6. Reporter (2017-10-02). "AMACO Movie Marketer Gave Me My 1st Break- Comic Actor, VICTOR OSUAGWU". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-01. 
  7. "Segun Arinze, Onyeka Owenu, Victor Osuagwu star in historical movie "The Chronicles"". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-11-07. Retrieved 2019-12-01. 
  8. "The Chronicles, a historical movie hits big screen". guardian.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 17 November 2018. Retrieved 2019-12-01.