Segun Arinze
Segun Arinze Listen (tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Segun Padonou Aina,[1] tí wọ́n bí ní ọdún 1965) jẹ́ òṣèrékùnrin ti orílẹ̀-èdẹ̀ Nàìjíríà[2] àti òǹkọrin.[3][4][5][6][7]
Segun Arinze | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Segun Padonou Aina 1965 (ọmọ ọdún 58–59) |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Obafemi Awolowo University |
Iṣẹ́ | Actor/Producer/PR/Talkshow host |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeÒun ni àkọ́bí láàárín àwọn ọmọ méje tí Lydia Padonu bí.[8] ÌlúBadagry, ní Ìpínlẹ̀ Èkó ló ti wá. Ilé-ìwé Victory College of Commerce ní Ilorin ló lọ, kí ó tó wá lọ sí Taba Commercial College ní Ìpínlẹ̀ Kàdúná láti parí ẹ̀kọ́ girama rẹ̀. Ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa Dramatic Arts ní Obafemi Awolowo University. Ó gba orúkọ ìnagijẹ Black Arrow làtàrí ẹ̀dá-ìtàn tó ṣe nínú eré ọdún 1996 kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ "Silent Night" èyí tí Chico Ejiro gbé jáde.[9][10]
Ó fẹ́ òṣèrébìnrin ẹgbẹ́ rẹ̀, tórúkọ rè ń jẹ́ Anne Njemanze, àmọ́ ìgbéyàwọ́ yìí ò pẹ́ rárá.[11] Tọkọ-taya náà bímọ obìnrin kan, tí wọ́n sọ ní Renny Morenike, tí wọ́n bí ní ọjọ́ 10, oṣụ̀ karùn-ún.[12]
Iṣẹ́ tó yàn láàyò
àtúnṣeSegun Arinze bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tó yàn láàyò gẹ́gẹ́ bí i akọrin àti òṣèré. Orin kíkọ ló kọ́kọ́ gbe síta gbangba, lẹ́yìn ṣàbéjáde orin kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Dream.[13] Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní kópa nínú fíìmù àgbéléwò ní ìlú Ilorin. Yàtọ̀ sí iṣé òṣèré tó yàn, Segun tún jẹ́ akọ́nimọ̀ọ́ṣe-fíìmù, tó sì ń ṣiṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú African international film festival, tó sì ń fún àwọn ìran òṣèré tó ń bọ̀ lẹ́yìn mu nínú omi ìmọ̀ rẹ̀.[14][15][16]
Àṣàyàn fíìmù rẹ̀
àtúnṣe- Across the Niger
- Silent Night
- Chronicles (pẹ̀lú Onyeka Onwenu àti Victor Osuagwu)
- Family on Fire (2011)
- A Place in the Stars (2014)
- Invasion 1897 (2014)[17][18]
- Deepest Cut (2018) - pẹ̀lú Majid Michel àti Zach Orji
- The Island Movie (2018)[19]
- Gold Statue (2019)
- Òlòtūré (2019)
- She Is (2019)
- Who's the Boss (2020)
- Blood Sisters (2022)
- Blogger's Wife (2017)
- Highway to the Grave (1999)
Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
àtúnṣeYear | Award ceremony | Category | Film | Result | Ref |
---|---|---|---|---|---|
2017 | Best of Nollywood Awards | Best Supporting Actor –English | Tatu | Wọ́n pèé | [20] |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Segun Arinze's debut album". punchng.com. Archived from the original on 14 August 2014. Retrieved 13 August 2014.
- ↑ Aileru, Islamiat (1 November 2021). "'Something big is coming' Segun Arinze links up with Pete Edochie and Kanayo O Kanayo for a new project". Kemi Filani News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 14 March 2022.
- ↑ "'The Heroes' unites Segun Arinze, Ifeanyi Onyeabor". vanguardngr.com. Retrieved 13 August 2014.
- ↑ "Segun Arinze, Onyeabor lead search for cultural heroes". punchng.com. Archived from the original on 14 August 2014. Retrieved 13 August 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Nollywood Star Actor, Segun Arinze Weds Lover". modernghana.com. Retrieved 13 August 2014.
- ↑ "Segun Arinze and Ann Njemanze with Emeka Ike – Exclusive". thediasporanstaronline.com. Archived from the original on 20 August 2016. Retrieved 13 August 2014.
- ↑ "AGN: Ejike Asiegbu, Segun Arinze back Ibinabo for re-election". vanguardngr.com. Retrieved 13 August 2014.
- ↑ "Segun Arinze Aina Padonu: Nollywood's timeless star". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 12 August 2017. Archived from the original on 5 October 2021. Retrieved 26 March 2021.
- ↑ "How Chico Ejiro inspired my bald look – Segun Arinze". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 February 2021. Retrieved 26 March 2021.
- ↑ "Sequel of Segun Arinze's 'Black Arrow' underway". thenationonlineng.net. https://thenationonlineng.net/sequel-segun-arinzes-black-arrow-underway/.
- ↑ "Nollywood actress, Anne Njemanze celebrates her daughter who turns a year older today". bioreports. Retrieved 13 October 2020.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Segun Arinze's Daughter Renny, Accuses him of Sending her 'fake' Happy Birthday Wishes on Instagram". motherhoodinstyle. Retrieved 11 October 2020.
- ↑ "Segun Arinze Aina Padonu: Nollywood's timeless star". m.guardian.ng. Retrieved 26 March 2021.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "nigeria.shafaqna.com". Nigeria News (News Reader) (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2 December 2019.
- ↑ "Segun Arinze The man once known as Nollywood's bad boy". www.pulse.ng. Retrieved 2 December 2019.
- ↑ Nigeria, Ckn. "My Dad Wanted Me To Be A Lawyer..Segun Arinze". Retrieved 2 December 2019.
- ↑ "Lancelot Imasuen's Invasion 1897 hits cinemas Dec 5". The Sun. Our Reporter. Retrieved 16 November 2014.
- ↑ "'Invasion 1897' Lancelot Imaseun's movie set for cinema release". Pulse Nigeria. Chidumga Izuzu. Retrieved 26 November 2014.
- ↑ "the island ( 2018)". nlist.ng. https://nlist.ng/title/the-island-1107/.
- ↑ "BON Awards 2017: Kannywood’s Ali Nuhu receives Special Recognition Award". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 23 November 2017. Retrieved 7 October 2021.