Wande Coal
Oluwatobi Wande Ojosipe tí a bí ní ọjọ kejidinlogun oṣù kẹwàá, ọdún 1985, tí orúkọ ìnagijẹ rè ni jẹ Wande coal jẹ́ ọ̀kọrin ti orílé èdè Nàìjíríà àti akọ-o.[1][2]
Wande Coal | |
---|---|
Wande Coal in December 2018 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Oluwatobi Wande Ojosipe |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Wande Coal |
Ọjọ́ìbí | 18 Oṣù Kẹ̀wá 1985 Lagos State, Nàìjíríà |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Years active | 2006–present |
Labels |
|
Associated acts | |
Website | official website |
Ìbẹ̀rẹpẹ̀pẹ̀̀́ Ayé
àtúnṣeÀbí Wande Coal ní ọjọ́ kejilelogun oṣù kẹwàá ní erékùṣù Èkó ní ìpìlè Èkó ní orílè-èdè Nàìjíríà. Orúkọ bàbá rẹ ń jẹ́ Olóyè Ìbùkún Olúfúntọ́ tí orúko ìyá rẹ̀ sì ń jẹ́ Omolará Olúwáyẹmísí ìkósínú. Wańde coal jẹ́ àbọkí láàárín ọmọ méjì tí àwọn òbí rẹ́ bi.
ÈTÒ Ẹ̀KỌ́
àtúnṣeÓ bẹ̀rẹ̀ ilé ìwé alákọ̀bẹrẹ̀ ni Staff Nursery and Primary School tí wá nì ìjànikin ní ìpínlè Èkó. Lẹ́yìn ní ọ tẹ̀sìwàjú láti lọ sí ilé ìwé ìjọba tí wọ́n pè ní Federal Government College ti ìjànikin ní ìpínlè Èkó fún ẹ̀kọ sẹ́kọ́ńdírì. O tún bọ́ tẹ́siwájú láti lọ sí ilé ìwé gíga yunifásítì tí ìlú Èkó ni bi tí o ti kẹ́kọ̀ọ́ gbọyè nínú iṣẹ́ Curriculum Studied.[3]
IṢÉ ṢÍṢE
àtúnṣeWande coal bẹrẹ si kọrin ninu ẹgbẹ akọrin ọdọ ni ile ijọsin rẹ. O ni isinmi akọkọ rẹ ni ile-iṣẹ ere idaraya Naijiria gẹgẹbi onijo. O bẹ́rẹ́ iṣẹ pẹlu (wole si) Don Jazzy ní ilé iṣẹ rẹ̀ Mo' Hits Records ni ọdun 2006. O ṣe àkópá ninu Awọ orin ti [D'banj]s' Rundown/Funk you up gbé jade, àwọn orin naa sìni Loke", "Tonosibe" àti "Why Me".
".[5] Gẹ́gẹ́ bí ọkọrin tí wọ́n gbà wọlé sínú Mo' Hits, o tun jẹ ọmọ ẹgbẹ ti Mo' Hits allstars ati pe o ṣe ipa pataki ninu itusilẹ CV ('Curriculum Vitae) album. Awo-orin ‘CV’’ àti ‘Ololufe’ jẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára àwọn orin ìfẹ ti omo Naijiria nífẹ̀ẹ́ sí tí ẹnìkan kan kò tíì kọ rí. Lẹ́yìn náà, Coal ṣe àwo orin àkọ́kọ́ rẹ̀ Mushin To Mo'Hits èyí tí ó jẹ́ ìtẹ́wọ́gbaà ní gbogbo orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, UK àti USA.[6]
Coal tí ṣe awọ pẹ̀lú àwon ọ̀kọrin orílè èdè Nàìjíríà mìíràn bí Ikechukwu, Phyno, Davido, Naeto C, Dr SID, D'Prince, Wizkid àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọ̀kọrin mìíràn. Ní ọdún 2012 ní ìgbésẹ nlá kan jẹwó laarin àwọn aláṣẹ Mo hits Don Jazzy ati D'banj, Coal, Dr'Prince ati [D'Prince]] fọwọ́ sí ilé iṣẹ orin tuntun tí Don Jazzy dásílẹ̀ tí orúko ilé iṣẹ náà sì ń jẹ́ Mavin Records pẹlú àfikún Tiwa Savage láti inú ilé iṣé idaraya (Record Label) tí ó ń jẹ́ 323 tí ó ń ṣe bí Ìyá-Àfin àkọkọ ti Mavin Records. Wande Coal fi Mavin Records sílẹ ní Oṣù kọkànlá ọjọ́ keje, ọdún 2013 nítorí jija ohun-ini orin kan èyí tí ọ jé ìkanna pẹlu awọn orin Don Jazzy. Ni Oṣu kọkanla ọdun 2013, o ṣe ifilọlẹ orin kan (single) tí à pè ní “Baby Face” gẹ́gẹ́ bí orin ìpínyà láàárín òhun àti Mavin Records. ..[7]
Ó gbé orin kan jáde ní ọdún 2020 èyí tí ó jé orin kàn ṣoṣo (single) tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ "Again", tí Melvitto ṣe.</ref> Ó kọ orin kan jade lọ́dún 2021 tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ "Come My Way" èyí tí o ń rin lọ́wọ́lọ́wọ́[8]
ÀWÒRÁN YÍYÀ ( Discography)
àtúnṣeStudio albums
àtúnṣe- 2009: Mushin To Mo’Hits
- 2015: Wanted
- 2020: Realms[9]
Compilation albums
àtúnṣe- Curriculum Vitae (2007)
- Solar Plexus (2012)
Singles
àtúnṣeYear | Single | Album | Producer | Label |
---|---|---|---|---|
2008 | "Bumper2Bumper" | Mushin 2 Mohits | Don Jazzy | Mo' Hits Record |
"You Bad"
(Featuring D'Banj) | ||||
"Taboo" | ||||
"Who Born The Maga" (Featuring KaySwitch) | ||||
2011 | "Go Low" | Mavin Records | ||
"Been Long You Saw Me" (Featuring Don Jazzy) | Don Jazzy | |||
"Private Trips" | Jay Sleek | |||
2012 | "See Mi Ri" | Solar Plexus | ||
"Forever" | ||||
"Pretty Girls" | ||||
2013 | "The Kick"
(Featuring Don Jazzy) |
Don Jazzy | Black Diamond Entertainment/ Mavin Records | |
"Rotate" | Don Jazzy | Mavin Records | ||
"Baby Face" | ||||
2014 | "My Way" | Wanted | Maleek Berry | Black Diamond Entertainment |
"Baby Hello" | ||||
2015 | "Ashimapeyin" | Wanted | Sarz | Black Diamond Entertainment |
|
Wanted | Da Beat Freakz | Black Diamond Entertainment | |
2017 | "Iskaba"
(Featuring DJ Tunez) |
Spellz | Black Diamond Entertainment | |
"Ballerz" | Maleek Berry | Black Diamond Entertainment | ||
"Oh No No" | CheekyChizzy | Black Diamond Entertainment | ||
"Funkeh" | Killertunes | Black Diamond Entertainment | ||
"Turkey Nla" | Spellz | Black Diamond Entertainment | ||
2018 | "So Mi So" | Juls | Black Diamond Entertainment | |
2020 | "Again" | Juls | Black Diamond Entertainment | |
2021 | "Come My Way" | Juls | Black Diamond Entertainment |
Gẹ́gẹ́ bí Àkópá ọ̀kọrin
àtúnṣeÀWÒRÁN FÍDÍÒ TÍ Ó WÀ NÍNÚ RẸ
àtúnṣeYear | Title | Album | Director | Ref |
---|---|---|---|---|
2013 | "Rotate" | Sesan | ||
2013 | "The Kick" | Sesan | ||
2014 | "My Way" | Sesan | ||
2014 | "Baby Hello" | Wanted | Sesan | |
2015 | "Ashimapeyin" | Unlimited L.A | ||
2015 | "Same Shit" featuring AKA | Studio Space Pictures (SSP) | ||
2017 | "Iskaba" featuring DJ Tunez | Sesan | ||
2018 | "Turkey Nla" | Unlimited L.A |
ÀWỌN Ẹ̀BÙN
àtúnṣe- African Artiste of the Year – Ghana Music Awards 2010[15]
- Artiste of the Year – 2010 Hip Hop World Awards[16]
- Best R&b/Pop Single – 2010 Hip Hop World Awards[17]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Monger, Timothy (1985-10-18). "Wande Coal Biography, Songs, & Albums". AllMusic. Retrieved 2022-02-22.
- ↑ "Wande Coal to release album soon". Vanguard News. 2015-01-30. Retrieved 2022-02-22.
- ↑ "Wande Coal: Biography, Early Life, Education, Career and Net Worth". Jenpedia. 2024-06-04. Archived from the original on 2024-06-12. Retrieved 2024-06-12.
- ↑ Vanguard (2015-01-31). "Wande Eédú láti tu awo-orin sílẹ̀ láìpẹ́". Retrieved 2015-04-22. Unknown parameter
|iṣẹ́=
ignored (help) - ↑ Vanguard (2015-01-31). "Wande Eédú láti tu awo-orin sílẹ̀ láìpẹ́". Retrieved 2015-04-22. Unknown parameter
|iṣẹ́=
ignored (help) - ↑ TheNETng (2015-03-15). /03/wande-coal-aka-collabo-on-new-song/ "Wande Coal, AKA kolabo lori orin tuntun." Check
|url=
value (help). Retrieved 2015-04-22. Unknown parameter|iṣẹ=
ignored (help) - ↑ Àdàkọ:Cite ayelujara
- ↑ Wande Coal - Come My Way (Official Video), archived from the original on 2017-03-18, retrieved 2022-02-28 Unknown parameter
|ọjọ wiwọle=
ignored (help); Unknown parameter|ede=
ignored (help) - ↑ "EP: Wande Coal – Realms". LOKCITYMUSIC.COM (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-09-10. Archived from the original on 2020-09-23. Retrieved 2020-10-01.
- ↑ Life & Times Of Killz Vol. 1 by Ikechukwu on Apple Music (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), 2009-05-25, retrieved 2017-12-22
- ↑ 11.0 11.1 U Know My P by Naeto C on Apple Music (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), 2008-08-01, retrieved 2017-12-22
- ↑ The Entertainer album on iTunes.
- ↑ "Patoranking, Wande Coal Duo share new 'My woman, my everything video'". Pulse Nigeria. Joey Akan. Archived from the original on 22 June 2015. Retrieved 12 June 2015.
- ↑ "Wande Coal x Shizzi - "Kosowo"". mp3naija. 16 January 2016.
- ↑ Ghana Music Award (2010-04-11). "Ghana Music Awards 2010 winners". Ghana Music Award. Archived from the original on 2015-04-14. Retrieved 2015-04-22.
- ↑ Vanguard (2010-04-30). "Hip Hop Awards: Wande Coal is Nigeria’s best". Vanguard. Retrieved 2015-04-22.
- ↑ CP- africa.com (2010-04-30). "Hip Hop Awards: Wande Coal is Nigeria’s best". CP- africa.com. Archived from the original on 2016-03-09. Retrieved 2015-04-22.
External links
àtúnṣe- Official Website Archived 2019-06-13 at the Wayback Machine.
- "Again" by Wande Coal