Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 10 Oṣù Kínní
- 49 SK – Juliu Késárì àti àwọ ọmo ogun re gba odò Rúbíkónì kọjá ní ìlòdì sí òfin Rómù, èyí bẹ̀rẹ̀ ogun abẹ́lé.
- 1920 – Àdéhùn Versailles bẹ̀rẹ̀ láti mú òpin bá Ogun Àgbáyé 1k.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1938 – Donald Knuth, aṣesáyẹ́nsì kọ̀mpútà ará Amẹ́ríkà
- 1949 – George Foreman, ajaẹ̀sẹ́ ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1778 - Carl Linnaeus, aṣesáyẹ́nsì ará Swídìn
- 1951 – Yoshio Nishina, onímọ̀ físíksì ará Japan (ib. 1890)
- 1957 – Gabriela Mistral, olùkọ̀wé ará Tsílè (ib. 1889)
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |